Wọn le awọn ọmọ Nigeria ni South Afrika poo!

Spread the love

Ohun to n ṣẹl si awn m Naijiria ti wn wa ni oril-ede South Afrika bayii ni ko ṣẹl nibi kan ri, gbogbo arinrin-ajo to j m oril-ede Naijiria ko l sibi kan ti wn ti n pa wn, ti wn si n fi kum ati ohun ija oloro mi-in le wọn jade. Looot ni bii dun 1970, nigba to di pe etor aje wn fẹẹ maa dnu kl ni oril-ede Ghana, wọn le awnm Naijiria ti wọn wa nib, wn ni ki wn maa pada l si ile wn. Wn le wn tiletile ati trutru wn, awn miiran to si ri e daadaa nibẹ, wn o j ki wọn gbe awn ileeṣẹ wn. Nigba naa ni kinni naa di orin bayii ni ilYoruba pe: ‘Kin ni n oo j gbagbe ile mi, kin ni n oo j gbagbe ile mi, ero Ghana ti k mi lgbn, ero Ghana ti k mi lgbn, kin ni n oo j gbagbe ile mi!’ Awọn ara Oke-Ogun si s orin naa di ijo, ti wn n k pe ‘Tile-tile lk ko wn wa o, tile-tile lk ko wọn wa, ero to l si Ghana, tile-tile lk ko wn wa!’

ugbọn nibi tir naa m niyi, ko snikan to pa nikan, ko si si ni to fiya j wn, ijọba loofin pe ki onikaluku maa l sile r. Bẹẹ naa lr si ri ni dun 1984 si 1985, nigba ti eto r aje Naijiria funra r ṣẹṣẹ fẹẹ maa dnukl, ti ijba ologun awn Muhammadu Buhari ati Tunde Idiagbn si ofin pe ki awn m Ghana ti wn ti kun Naijiria ff nigba naa maa waa l sile. Ijba Naijiriae e debii pe wn wa mto ti yoo ko awọn eeyan naa, koda wn tun fun awn mi-in lowo ninu wn. Ko snikan to lu ọmọ Ghana kan, tabi ti wn gun wọn lb, ka ma ti i s pe wn yoo pa wn. Ohun toe n ya gbogbo aye lnu pe awnm oril-ede South Afrika n e bayii si awn eeyan wa, ti wn mura lati pa wn ti wọn ba ri wn, ti wn si n fiya to ba wu wọn j wn, latari pe wn ni ki wn kuro ni oril-ede awn. Iyat eyi ni pe ki ie ijba South Afrika lo ofin.

Ohun ti awn eeyan n s aa ni pe ijba oril-ede naa ko le s pe oun ko m tabi pe oun ko lw si ohun ti awn eeyan yii n e. Koda, awn gb ij Katoliiki nib s pe ki ijọba ma pur m pe r naa ki i ṣe tilyamya, tabi oniluumlu, wn ni ki wọn fi ir ti wn n pa silẹ pe awn daran ni wn n le jade. Wn ni bo ba j daran ni wn n wa, e ko si daranm oril-ede South Afrika ni, bo ba si j awn ti wn n ta oogun oloro ni wn n wa, ki lo de ti wn ko l sid awnm South Afrika to j gbogbo eeyan m pe iṣẹ ti wn n ṣe niyn. Ki i e awn ij Katoliiki yii nikan ni wn sr ni South Afrika, awn mi-in naa da si i, wn si fsun kan ijba wọn pe o n gbe lyin awn adaluru ti wn n fiya j awn m Naijiria, ti wn si n pariwo pe ki wn jade. ugbọn nibi ti r naa le de bayii, ko j pe apa ijba paapaa ka a m rara, iyẹn ijba wn loril-ede South Afrika.

Wn ti n e kinni naa tip, ugbọn eyi ti wn e gbẹyin yii le di, nitori wn ba nnkan j ju bo ti y l, bẹẹ ni wn si pap eeyan, ijọba oril-ede naa ko si ri awọn daran kan mu. Ni awn ilu to wa ni agbegbe Johannesburg, ni ija naa ti br nij kin-in-ni ou ta a wa yii, ugbọn wn o pana r titi di j keji, ou yii, nigba ti yoo si fi dij kta, awn onijangbn naa ti w ilu Johannesburg, ilu kan to da bii Eko tiwa yii, to j nib ni okoowo oriṣiiriṣii ti n l. Nigba ti wn de Johannesburg yii, nnkan yipada lsks, nitori bi wn ti n kan awn ṣọọbu to j ti awọn ọmọ Naijiria ni wn n duro, ti wn si n klu awọn ṣọọbu yii, ti wn n f wn, ti wọn si n ji gbogboja to ba wa ninu r ko l. Awn kọọkan ninu awn m oniwahala yii ti wn ti da awọn m Naijiria kan m, ile wn, tabi ṣọọbu wn, tabi idi mto wn ni wn n l.

Ki oloju too ṣẹju, wọn yoo ti ba mto naa j, tabi ki wn ji gbogbo ohun ti wọn ba le ta lara r y, onimto to j m Naijiria naa yoo si ti sa l. Bẹẹ ni wn fi bii j mrin si marun-un ja ija naa, ti awn ijọba oril-ede naa ko si rinikni mu ninu awn m wn to n dalu ru, ti wn si n fiya ainidii j awn alejo to wa ld wn. r naa dija laarin awn oril-ede mejeeji paapaa, nitori ijọba Naijiria binu. Awnm Naijiria mi-in funra wọn naa binu, ti wn klu ileeṣẹ ti wn ro pe ti awn ara South Afrika ni, iyẹn Shoprite ati MTN, wn si mura lati ba wọn j. Ohun ti wn ko m ni pe ọpọlọpọ awn ti wn niṣẹ ni awọn ileeṣẹ wnyi, awn ọmọ Naijiria bii tiwn ni. Nigba ti awn ara mbasi ri i bi kinni naa ti n l, iyn ileeṣẹ to n oju ijọba South Afrika ni oril-ede yii, kia ni wn timbasi naa pa, ti awọn oiṣẹ ib si sa kuro, nitori wn o m ibi ti awọn ọmọ Naijiria le gba y si wn.

Ijọba Naijiria naa si tieto nimbasi tiwn to wa lhun-un pe m Naijiria to ba etan ti yoo l sile, awn yoo eto bi wn yoo e ko wn pada. Nigba naa ni ileeṣẹ lk-ofurufu Air Peace ni gbogbom Naijiria to ba fẹẹ wale pada, f lawn yoo ko wọn lati hun wale. Awn alaṣẹ mbasi Naijiria ni South Afrika si ti kede  pe jruu, Wsidee, ni wn yoo maa br si i ko awọn eeyan naa, nitori bii irinwo (400) lo ti forukọ sil lal j Satide to kja yii pe awn fẹẹ l sile, awn o gbe South Afrika m, nitori wn ti ba gbogbo okoowo ti awn jokoo ti nib j, awn o si le j ki wn waa gbẹmi awn lojiji. Aar oril-ede naa paapaa, Cyril Ramaphosa, ranṣẹ si Aar Muhammadu Buhari pe iru nnkan bẹẹ ko ni i ṣẹl m, awn yoo wagbọn da si i, pe awn aar mejeeji lawn yoo j yanju rNigba ti Buhari si gbọ eyi, o mura pe oun yooe abwo si oril-ede naa lou to n b.

Ṣugbọn iyẹni wọn n s lw nigba ti wahala tun ru jade lj Sannde. kunrin ajijagbara kan to tun j olori gbẹ oelu nib, Mangosuthu Buthelezi, lo pe ipade, to si ni oun yoo ba awn m orilede naa sr. Nibi ipade yii ni wn ti br si i pariwo le e lori, ti wni ko fi awn sil, kia lawn ero si ti bẹr ariwo, n lawn ọmọ South Afrika ba tun ya sigboro, ariwo ti wn si n pa ni pe ‘A ko f alejo! A ko f alejo o! A ko f alejo nil wa o! Ki onikaluku yin gba ilu l!’ Kia lr naa ti di rogbodiyan, ti wọn si ti pa ni kan lsks, ti awn marun-un mi-in si farapa yannayanna. Iroyin ti ALAROYE gb ni pe ki ie awn eeyan mi-in lawn m South Afrika yii dojuk gan-an, Naijiria gan-an ni wọn f ki wn kuro ni oril-ede awọn, wọn ni awn ko f wọn m. Awn ọmọ Naijiria paapaa naa si m, ninu ibrubojo ni pup ninu wn wa, wn n wa gbogbo na lati pada sile ni.   

Awn miiran ninu awn eeyan yii s pe awn ko le waa ku si ilu oniluu, ohun yoowu to ba wa ni South Afrika, awn yoo fi i sil ki awọn maa pada b ni oril-ede tawọn. Awọn m South Afrika si ree, awn ti ni awn ko ni i gba kim Naijiria kankan duro, wni awọn ko f alejo bii tiwn. Nigba ti ijọba ko si da sir naa bayii, mi awọn eeyan naa ko de nib m, nitori nigbakigba ni ijamba le e wn. Ohun to fa a niyi to fi j bi wn ba ti br si i ko awọn m Naijiria yii, lrun lo m j ti wn yoo ko wn tan, nitori pup ninu wn lo fẹẹ pada sile, wọn lawọn ko gbe ni ilẹ ajoji yii m o. Bayii ni awọn ọmọ South Afrika le awọn ọmọ Naijiria ni oril-ede wn, ti wn si n leri pe ni ti ko ba lọ, pipa ni wn yoo pa a. Ṣugbọn rnaa ko le tan sibẹ, awn nnkan kan yoo ti idi r y, nitori ọplọpọ awọn oril-ede Afrika, ati awọn oril-ede agbaye ni wn koriira ohun ti awọn ara South Afrika yii n e. Bi awn naa si gbn ju aarun l, wn yoo jiya ohun ti wn ne yii o!

(46)

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.