Wọn fẹsun kan Ọlọfa tilu Ọffa, wọn lo n gba ile onílẹ̀

Spread the love

Awọn ara adugbo Ijehu, ilu kan to wa ni eyin odi ilu Offa lo ti fehonu han si bi Oba ilu naa, Mufutau Gbadamosi, Ọlọfa tilu Ọffa ṣe n fipá gba ilẹ awọn. Iwaju ile igbimọ aṣofin nipinlẹ naa ni wọn ti fi ibinu wọn han si Ọba naa.
Oriṣiriṣii àkọlé ni wọn gbe lọwọ, ti wọn si n kọ orin lati fi aidunnu wọn han si iwa Ọba naa. Baálẹ̀ Moshood Adeogun, to jẹ baalẹ Agbegbe naa ni niṣe ni Ọba Esuwoye n tẹ àṣà ilu awọn loju pẹlu ilẹ to n fipá gba naa, nitori iṣẹ àgbẹ̀ ni awọn n ṣe

 

.

(18)

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.