Ta ni yoo si sọ pe Makinde naa ko ṣeun

Spread the love

Gomina ti ipinlẹ y, eyi Makinde, kede ls to kja pe oun tietan lati san owo ti ijọba ipinl Ọṣun to kja l j, ti ko fi j ki wn ri owoou ati awọn owo mi-in san fawn oiṣẹ Yunifasiti Ladoke Akintla, ni Ogbomọṣọ, ti ileewe naa ko si le iṣẹ wọn lati bii p dun syin. Awn nnkan mi-in wa to tiiyan loju ju ole jija l, iru ni ohun ti ijọba Ọṣun to kja l, lab Raufu Argbẹṣọla e nipa r awọn yunifasiti Ọṣun yii. Awn mejeeji ti wn n ejba nib, APC ni wn, oun plu Isiaka Ajimbi. Wọn eto inawo ileewe hun ti, wn ko sanwo ou, wn ko sanwo oiṣẹ, wọn ko sieto bawn mleewe yoo e maa kawe wn. Lasiko tiwn, gbogbo nnkan dorikodo fun ileewe naa, boe ri gl lasiko ti awn Akala ati Oyinlla PDP n ejba tiwọn naa ni. Ae ko si iyat gidi kan ninu awọn oloṣelu ti a ni yii, gbọn ori kan naa lo p ninu wn, afi awn kọọkan to ba dara ninu wn. Abi nigba ti ijọba ilYoruba meji ko ba le da e akoso yunifasiti kan daadaa, ki lo waa tun buru ju bẹẹ l. Yunifasiti ti awn araalu funra wn n da sil, to waa de ori akayin ti akara di eegun. p nnkan lawn eeyan ti wn kja l yii fi oṣelu baj, ijamba buruku si p ninu awọn ijọba ti wn e. Ki lrun ma j ka ri iru tiwọn m lagbegbe wa. Ọlọrun yoo ran Makinde lw, yoo le e bo tie fẹẹ e. Bẹẹ l’Ọlrun yoo ran Oyetla Ọṣun naa lw, oun naa yoo le da si idagbasoke yunifasiti yii, awn mejeeji yoo si le j gbe ogo ilẹ Yoruba ga. Yoo ee e o, lagbara Ọlọrun.

(2)

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.