Ta ni yoo gba ilẹ Yoruba lọwọ gbese ajogunba

Spread the love

 

Ileeṣẹ to n ri si eto ẹyawo oril-ede yii lab ijọba apap kede ls to llhun-un pe ninu gbogbo awọn kun to wa loril-ede yii, awkun Guusu-Iw Oorun, iyn ilẹ Yoruba, ni gbese wpọ jul. Wn ni wn jgbese naa debii pe awn ni wọn wa ni ipo kin-in-ni ninu awọn onigbese ni Naijiria. Ohuti eleyie ri bẹẹ, awn oloelu il wa nikan lo le s o. Bi gbogbo kun ba n j gbese, ki i ṣkun tiwa, bi a oo ba tilẹ waa jgbese, ko ni i j awa ni oo wa nipo kin-in-ni. Bẹẹ ni ki i ṣe nitori iṣẹidagbasoke kankan o, nitori ariwo lasan lo p ld wa nibi, awn ipinlmi-in wa ti wn n e daadaa faweeyan wn ju awn ti a ni ld tiwa yii l o, bẹẹ ni wn ko si ri owo gidi kan gba ld ijba. Ni Naijiria ti a wayii, bi a ba ti mu ijọba apapọ, ko tun si ibi ti wn ti n pa owo to ju ipinlẹEko l, bẹẹ ipinl Eko yii, laarin awa Yoruba lo wa. Ki la waa n j gbese to pọ to bayii si? Ki lo de ti tiwa le to bẹẹ. Ko si ohun to fi le to bẹẹ ju pe oṣelu ko-l-nil-ko-dowo, oelu owo-lwyin-nil bii ti aṣẹwo la n e. Awọnaraalu nko m, awn eeyan wa ko ja si i, pe owo ti awn oloelu n ha le wn lw, owo ti wn n lọọ gba ld awọn aṣaaju gbẹ oṣelu gbogbo, ankara ti wn n da fun wn, irsi ti wn n ra fun wn, ati awn nnkan mi-in ti wn n fun wn kiri, owo wn, owo to y ki wọn fi ṣe nnkan rere, owo ti wn ya lw awn oyinbo tabi wọn lọọ ya nibomi-in, owo naa ni wn n na fun wn yn. Awn oloelu ti  ri yii ko ko owo kankan wa, owoAbu ni wn fi n ṣe Abu lalejo, owo yin ni wn n na fun yin. Bẹẹ ki i ṣpe wn yoo na gbogbo owo naa fun yin, bi wọn ba ji gbrun kan Naira,grun-un ni wn yoo na fun yin, awn yoo ko ẹẹdgbrun to ku sapo ara wn, wn yoo si sare fi i ranṣẹ siluu oyinbo fun awọn ati awmwn. yin araalu naa o si le beere pe ki lo de, nigba to j yin naa ti gba owo ti ko y ki ẹ gba,  ti j ijkuj ti ko y ki ẹ j. Gbese ti awn ti wn n ṣe gomina ilẹ Yoruba n j, paapalati bidun mwaa syin bayii ki i ṣe gbese ilsiwaju, gbese ti yoo fa ilẹ Yoruba syin ni. e eeyan kale ka iyegbese ti Argb j silẹ fun wọn l‘Ọṣun ni! Awn ti wn wa loye bayii, atawnm wnko le san gbese naa tan, nigba ti awn oloṣelba si brariwo wn, wn yoo ni ijọba Argbẹ e daadaa fun wọn l‘Ọṣun.  beere iṣẹ daadaa to ṣe, ki ẹ si gbe e sgbẹẹ gbese to j oo ri i pe bii ni to lu awn ara Ọṣun ni jibiti ni. Ki i ṣe Argbẹ nikan, bo ṣe kari ilẹ Yoruba yii niyn, awn gominwnyi kan n j gbese ni, gbese buruku, wn yosi s fun yin pe ijọba ti awọn ṣe lo dara julugbọn a n pariwo o, awn eeyan ni ki i gbọran o, iwnba owo di ti wn yoo fi ta wa lr ti j ki laakaye p par, ati awn ti awọn oloṣelu si n lo fun iṣẹ aburu ti wn ṣe. Bi wn n fib la lomi-in lara bayii, yoo maa s pe ko si bi oloelu naa ko ṣe jni, ko maa ge oun law ara nio. Titi ti thun yoo fi pa a jaye, ti yoo fifowo oun ati tawọm r gb bukaata tir ati ti idile r, yoo maa tle e biiran naa ni. Oun lo del yii o, ta ni yoo gba ilẹ Yoruba lw gbese ajogunba yii o!

(20)

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.