Ọrọ aṣaaju Yoruba ti wọn ni wọn yan n’Ibadan

Spread the love

 

Bo e ba yin lojiji naa lba emi naa lojiji o. Gbogbo ẹyin ti ẹ kwe,yin ti  si beere r, ati yin ti  fi ibinu han lori r yii, ohun ti mo fẹẹ sọ fun yin ni pe bo ṣe ba yin lojiji yn gan-an nalo ba emi naa lojiji. r yiyan aaaju Yoruba to ṣẹl ls to kja ni mo n wi, nibi ti awọn kan ti jokoo sibi kan ni Ibadan, ti wn ni awọn yangbn wa, Purofs Banji Akintoye, gg bii aaaju Yoruba. yin naa kuku m pe ariwo ti mo n pa lati ọjọ yii niyi pe ki a ni aaaju fun Yoruba, pe ta ko ba ni aaaju, Yoruba ko ni i l sibi kan. Awn oloelu ti bu mi titi, wn ni aaaju wo ni mo n wa, wni Bla ni aaaju tawn. Mo ni mo ti gbugbọn emi mọ pe Blki i e aaaju temi, aaaju awọn oloelu ni. Awn kan naa bu mi, wni aaaju wo ni mo tun n wa, pe aaaju Afnifre ni aaaju Yoruba. Mo ni mo ti gb, mo a mọ pe aaaju Afnifre k naaaju Yoruba ti emi f, nitori aaaju Afnifre n oelu, aaaju Yoruba ko si gbdọ ṣoelu.

Aaaju ti mo n wa fun Yoruba, aaaju ti ko gbd fi sibi kan ni, aaaju ti yoo da duro gedegbe, ti yoo le da ti aarán fun aarán, ti yoo da ti aàràn fun aàràn, aaaju ti ẹnu r yoo tol nibi gbogbo laarin awọm Yoruba ni mo n s. Aaaju to ṣpe nigba ti  ba darukọ r, gbogbo Yoruba yoo dide naro pe aaaju awn ni. Aaaju bayii ko gbọd j oloelu, nitori bo ba j oloelu APC, m Yoruba to ba wa ninu PDP tabi ninu gbẹ oelu yoowu ko ni i gbpe aaaju oun ni. Bo ba si j PDP ni aaaju naa n ṣe, epe ni awnm Yoruba to ba wa ninu APC tabi gbẹ yoowu yoo maṣẹ binikni ba pe e ni aaaju niwaju wn. Nidii eyi, ohun akk ti ni tiyoba j aaaju Yoruba yoo ni ni pe thun ko ni i ṣe oṣelu rara, ohun pataki keji si npe ẹnu gbogbo Yoruba, tabi ẹnu ọpọlọpọ ọmọ Yoruba, gbd ko le thun lori pe aaaju ti awn f ni.

 ri i, ti a ba fẹẹ sọ ọ, loni-in ni il Yorubakan ninu awn ti a le mu ni aaaju, ti ipo naa t si (bo ba jẹ ẹlomi-in tun wa), ni gbn wa yii, Purofsọ Banji Akintoye. mwe gbaa ni, o si ti ṣe oṣelu ri,ọkan ninu awọn ọmọ ẹyin Awolọwọ ni: o ti ri okun, o ti ri ọsa, o ti kọ ọplọpọ iwe lori itan m Yoruba, ati ilsiwaju wn, agbalagba si ni, mọ ọdun mrinlelgrin (84), eyi ja si pe gbogbo ohun ti eeyan le fi e aaaju Yoruba ni baba yii ni. O dagba, o mwe, o mtan, ko si ṣe oelu m, iru ni ti a n wa niyn ti yoo le dari gbogbo wa. Ṣugbọn ki i ṣe ninu horo, laarin ilhotohoto kan, ni awn kan ti awọn mkunnu il Yoruba ko m, ti awn majesin ko m, ti awn brkinni ko m, yoo ti a ara wn jọ pe awn n yan aaaju le awa to ku lori. Nnkaarifin, iwsi ati gbin gbaa ni. Ohun ti ọrnaa fi daru lati il ree, nitori ko si iran ti i e bayii yan aaaju tiwn.

Nigba ti ariwo r yii degboro, ni ti mo kk pe (oun ni mo maa n pe ti r ba da bayii nitori oun ri iml aarin aweeyan yii ju mi l) ni aburo wa, ga Alaroye, mo ni ewo ni wn tun gbe de yii o? Ṣe o m nipa r ni? O ni oun ko le s pe oun mọ nipa r, oun ko si le sọ pe oun ko m nipa r. O ni jẹẹjẹ oun ni oun jokoo ni ọọfiisi kekere kan to n e iwadii nipa aa ati ie Yoruba ti awn Alaroye ni sinu gba Yunifasiti Ibadan, nib ni ni to pe apej ti wn ti yanni ti wn pe ni aaaju awn Yoruba yii ti waa ba oun. O ni thunalaye il kun foun pe awọn ti etan lati yan aaaju fun Yoruba, ati pAkintoye lawn mu, awn kan nilo owo di lati fi e eto naa ni, nitori gbogbo ẹgbẹ ajijagbara ilẹ Yoruba ni wn fẹẹ fi gbn yii jaaaju. O ni bi awn ba ti yan aaaju awn, eto ti yoo kan ni lati ko gbogbo Yoruba kuro lab Naijiria.

Alaroye ni oun s fun wọn pe bi eto naa ti dara to, na ti wn fẹẹ gbe e gba ni yoba a j. O ni oun alaye fun ni to wa yipe bi wn yoba yan aaaju fun Yoruba, nj wn ti ba awn aṣaaju inu Afnifre sr, nj wn ti ba aweeyan ti wn wa nijọba sr, awmYoruba ti wn di aṣẹ oṣelu agbegbe wa mu bayii, nj wn ti ba awn olori ọja sr, nj wn ti ba awn olori onimto, olori lran sr, njẹ wn ti ba awn ọjgbn ati mwe il Yoruba sre wn si ti ṣalaye r naa fun awọn ọba. Alaroye ni kunrin naa ni awn ko ti i ṣe gbogbeleyii, awkasa mọ pe awọn ti ṣetan lati yan aṣaaju Yoruba ni. O ni oun waa s fun un pe iru aaaju ti wn ba yan bẹẹ, wn yokan fi ni nae yy lasan ni, nitori aaaju tinu r ko ni mul, aaaju ti ko ni i le paṣẹ nibi kankan, aaaju ti ko sni ti yoo gbọr si lnu ni, koda araalu ko ni da a mọ ni.

O ni oun tun alaye pe yatọ si eyi, owo ti ọkunrin naa n wa kiri lati fie eto yii ko dara, nitori bo ba j gbogbo agbajọ ẹgbẹ ọm Yorubalo fẹẹ ṣe e, ti gbogbeeyan ba fwọ si i, kb kan bayii ko ni i ti apo awọn to ba wa nidii eto naa jade, araalu funra wn ni wn yoo nawo loryiyan aṣaaju wọn, ki i ṣe ohun to dara lati maa tr owo kiri pe a fẹẹ yan aaaju. Alaroye ni kunrin naa ni oun gb, ounyoo maa lọọ ro o, bo ba si e tun j, oun yoo j ki oun gb. O ni eyi ti oun yoo tun gb ni ti pe wn yan Purofs yii. O ni bi oun ti gbọloun pe jgbn Banji, ohun tsi s foun ni pe looot lawọn ọmnaa ti waa ba oun ni bii ou mrin syin, ugbọn oun sọ pe ohun ti wn fẹẹ ṣe yii ko ṣee e lasiko ti a wa yii, afi ki gbogbo ẹnu Yoruba ko le r naa lori ki oun too le gba iru ipo bẹẹ, nitori ninu awọn aaaju gbẹ Afnifre loun naaẹgbẹ awọn si ni ni to j olori pata.

Nigba ti mo ti gb gbogbo eleyii lnu Alaroye, kan mi baldaadaa, nitormo mọ pe bo ba j emi naa ni, ohun ti n oo wi, ati igbes ti n oo gbe naa lo ti gbe yii. Kinni kan lo wa nil wa bayii, iyn naa ni pe gbogbo ioro to n koju Yoruba lwlw, awn kan ri i laarin wa bi na lati maa fi i jun ni, bẹẹ ni awọn mi-in ri i biina lati maa fi wa orukọ fun ara wn, ti wn yoo si fi oruk nae oṣelu, ti wn yoo waa maa ba awa ti a j n e tl ja, ti wn yoo ni a ko m ohun ti awn ri nile ijba ni. Asiko yii ki i ṣe asiko ti a gbdọ ba ara wa ja, bẹẹ ni ko gbọd si ikunsinu kan laarin iwnba awn ti a n ri bayii ti a n pe ni aṣaaju wa. Eyi ti awn eeyan yie yii, wkan fẹẹ fi da wahalsil lasan ni. Akk ni pe wn ko laṣẹlati dọ ẹnikni, boya lati d mkunnu tabi lati d awọn araalu ti wn jẹ ọmọ Yoruba, wn ko si ni aṣẹ lati d awn ọba tabi agbaagba ilu lati yan olori fun wa.

Iru olori bẹẹ k la n s. Iru olori bẹẹ k la nilo. Awkaninu wa ti oju ti n kan latjọ yii, koda wọn n ba mi ja, wni mo n srọ aṣaaju, mo tun pa a ti, awn mọ pe aṣaaju gidi ni Yoruba nilo lasiko yii. N ko pa a ti, n ko si mnu kuro lori , o kan j n ko kọ ọ si oju iwe mni. Iṣẹ ni a n e labl, ki a le ri aaaju ti ki i ṣe oelu. Alatilyin awn Bla pẹlu gbẹ oelu wni Alani (Akinrinade), bẹẹ naa nigbn Wle (oyinka), alatilyin awn PDP ni gbṢẹgun (basanj), bẹẹ naa lawn mi-in ninu awn aṣaaju Afnifre dojuk PDP, ti awn mi-in si da tiwn sil ti wn pe e ni SDP. Yoooro lati fa aṣaaju Yoruba ti a n wi yọ laarin awn yii, nitori bi  ba mu ni to fi sd awn APC, awọn ti PDP yoo ya a bal, bo si jtawn PDP l mu, awn ti APC yoo fa thun ya prpr. Bẹẹkoko kan wa ninu rọ yii, iyn naa ni pe ko si aṣaaju Yoruba ti yoo lee ohunkohun ti awn ti wwa nijọba il Yorubbayii ko ba fwsi i. Nibti r naa ti ta koko niyn.

A oo maa ba r yil ls to n bugbọn mo kan fẹẹ fi yin lkan balpe gbn wa, Banji Akintoye, ko gba ki wn yan oun ni aṣaaju Yoruba lai j pe gbogbawọn to ku lo fwọ si i o, eyi ti awn kan lọọjokoti wọn ṣe nIbadan yii, wn kan fẹẹ fi ba awn ohun daadaa to wa nilẹ j ni o. A ko ti yan aṣaaju fun Yoruba, lj ti a ba fẹẹyan aaaju fun Yoruba, gbogbo yin ni ẹ oo gb, ti ẹ oo si fw si i, oju gbogbo yin ni yoo si ṣe.

(42)

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.