Nigba ti mo sun ti n ko le sun, mo tun ronu ọna abayọ kan

Spread the love
Fọto apejuwe: Ọkan lara awọn ọlọla Yoruba laye atijọ

Ọrọ kan ni mo fẹẹ sọ, bi eeyan ko ba si farabalẹ lati gbọ ọ, ọrọ naa yoo da bii isọkusọ lasan ni. Bẹẹ ọkan mi n s fun mi pe ki i e iskus, r to n ṣẹl yii naa lo mu ironu mi l sib, ti mo si n wona ati gbn ti a le da si i. N ko m boya aie ni iru awae nigba ti a wa ni kekere tabi ki i e aie, n ko si m boya r naa ba aye ode-oni tabi aa alakwe tabi ti sin wa mu, ugbn r bi ilYoruba koe ni i b sw araata, ti awn m tiwa nil yii ko ni i pada waa di ru ni mo ro deb, mo si ro pe o y ki n tete ta awn eeyan wa lolobo, o y ki n tete s ero ọkan temi sita, bi kinni naa ko ba si mu gbọn wa lonii, o ee e ko mu gbọn wa lla. Mo sun kaakaa, mo ronu titi lori r awn m HausaFulani ti wn n fi ojoojum ya w il Yoruba yii, kan mi si s fun mi pe ti yoo ba fi di aadtadun tabi gtadun si asiko ti a wa yii, awn eeyan naa yoo p ju wa l ni iltiwa nibi yii, ko si si ohun tinikni le e si i.

Bi wn ba n e bayii ya wle, ti a ko si le da wọn pada, ti a ko si le ni ki wn ma iṣẹ tabi ki wn ma gbe ilẹ wa, ti ero si p ld tiwn debii pe bii gbẹrun kan tabi ju bẹẹ l lo n de si il Yoruba yii ls kan, ko ni i pko ni i jinna ti wn yoo fi ba wa dgba. Wiwa ti wn n wa yii ko ni wahala, nigba ti wn ba br si i bim ni nnkan. Awn eeyan yii ko m m kekere i bi, nibi tini kanoo ti le bi ogun si ogoji m, ka ma ti i s awọn mọ ọm r, jmeloo ni wn yoo fi le wa ba ti wn yoo si ya wa silnilẹ wa. Boya wn ko awn ọmọ wọn l sileewe tabi wn ko l k la n wi, boya wn lkọọ tabi wn ko ni i k la n sọ. Ohun ti mo n wi ni pe wn p ju wa l. Bi wọn ba l sileewe, yoo tildaa di, ti wn ko ba l rara gan-an lewu, nitori iwa ti wn yoo maa hu ko ni i yat si tiranko, yoo buru ju iwa awnmọọta l, nitori awn mọọta Yoruba ki i paayan, ipanle lasan ni wn.

ugbọn nigba ti awọn mọọta ti awn alejo to n r wa yii yoo ba dagba si aarin wa, ipaayan ati ifagidi gba ohun olohun ko ni i j kinni kan loju wn, nigba ti wọn si m pe awn p ju wa l, awọn lagbara ija ju wa l, akoko perete ni yoo na wn lati maa s pe pawn lawn ni ilyii, ki ie awn m ti iru awa ba fi silẹ si aye l. ni to ba si fẹẹ maa e bii ni to m itan ninu wn, wn yoo da seria iku fun un. Ibeere to y ka beere lw ara wa ni pe bawo ni awa tie e ti awn m Hausa-Fulani n p ju tiwa l, nigba toe pe igba kan ti wa ti a ko jinna sira wa. Bawo lo e waa j toe pe wn ti le ni idaji apapọ awa Yoruba plu awn Ibo bayii, bẹẹ ko ri bẹẹ tl rara. Ko si ohun to fa a ju pe a fina awn baba wa sill, a yra fun iwa wn, a n s pe gbogbo ohun ti wn n e ni ko dara. A s aa tiwa nu, a ji toyinbo gbe; a dori sin kodo, a ni bi awọn baba wa ti e aye wn ko dara.

Igba kan ti wa to j nilẹ tiwa naa nibi yii, ohun ti wn fi n da awnlla ilu ati lr m ni iye iyawo ti wn ba f, ati iye awn m ti wn ba bi. Baba kanoo a maa fyawo mrin marun-un, awn mi-in a si maa f ju bẹẹ l, gbogbo wn ni yoo si e abiyam. Bẹẹ ni ki i e gbogbo awn ti wn bi m rpt yii ni wn ko lowo lati t wn o, p lo bim r ti ko f ko kawe nitori wn ko f ki wn di Kristni tabi ki wn fun wn loruk sin naa, ọpọ lo si bi awn m r ti ko nigbagb ninu k iwe rara, bẹẹ ni p bi awọn ọmọ r to f ki wọn maa ba oune iṣẹ ti oun n ṣe. Eleyii ki ie pe wn ko ri owo t wn tabi pe wn ko ni owo lati gb bukaata wn. Ki i e awn ti ko lowo ti wn n ko iyawo j ni mo n s o, awn ti wn lowo to le b odidi ilu, ti wn si fi owo naa f iyawo pup ti wn bim rpt. Koda awn mi-in tawnm ti wn bi doju ami gedegbe.

Ohun ti yoo si ya awọn eeyan lẹnu ni pe ati Musulumi ati awọn aṣaaju Kristẹni ni wọn n ṣe bẹẹ, ti wọn n fẹyawo ti ki i ṣe ẹyọ kan. Awọn eeyan n ro pe aṣa inu bibeli ni ka fẹ iyawo kan ṣoṣo, ṣugbọn ki i ṣe bẹẹ! Nitori ko si ibi ti lrun tabi Jesu Kristi ti pa a laṣẹ bẹẹ. Bo ba si j o wa nibi kan ti n ko m, yin lsin wnyi jwọ,  sọ ọ fun mi. N ko f ki  alaye amran Paul fun mi o, nitori mo m iyn daadaa. Ohun ti mo n f ni ibi ti lrun tabi Krisiti ti pa a laṣẹ pe kunrin kan ko gbd f ju iyawo kan l. Ko si ni ti ko m itan Abraham baba Igagb ati awọn iyawo r, ka ma ti i s ti Dafidi tabi ba Solomon, ati awn ojiṣẹ lrun nla nla miiran ti a gbọ orukọ wn. Ki e pe awn eeyan wnyi kuku g, bẹẹ ni titi doni ni a n fi orukọ wn gbadura, nitori Ọlrun ko s fun wa pe aie ni wn e. 

Fọto apejuwe lasan leyii o

Ohun ti eyi kọ wa ni pe aṣa awọn oyinbo ni aṣa naa, o si fẹsẹ rinlẹ daadaa ni Britain nitori pe ijọba obinrin pọ lọdọ tiwọn ju ijọba ọkunrin lọ, nigba to si jẹ Britain yii lo n ṣe akoso idaji aye nigba kan, ohun ti wọn ba ṣe nibẹ, dandan ni ki gbogbo aye ṣe e. Bẹẹ r naa ti di wahala si awn oyinbo funra wn lrun bayii. Bi o ba j wn rigbn r da ni, oyinbo ko ni i gba ki eeyan dudu maa w oril-ede awọn. Ṣugbọn nitori pe wọn ko ni awn m to p, awn obinrin wn ki i bim, awn alakwe kunrin naa yoo bi m kan tabi meji, awn obinrin mi-in yoo til ni awn ko bim m laye awn, eyi ni wn ki i e ni awn d to p to latie awn iṣẹ wn to y ki wn e, ti wọn yoo si maa wa awọn alejo, paapaa awn eeyan, dudu ti wọn yoo maa ba wn e e. Eyi lo fa a to n j ki oril-ede China di aaaju aye, nitori bi wn ti p to, ati bi wn e maa n ya lplọpọ w oril-ede kan.

Bi awọn baba wa ti e tl ree, ti awn to lowo laarin wn n biplọpọ m. Ofin ti a n tẹle yii iba dara bo ba j oril-ede ti a wa yii, awa nikan la wa nib, to j a n da gbe ilwa bii ti awn oyinbo yii ni. ugbọn ni oril-ede tiwa, ya nla mta lo wa nib, awn ya meji to ku n bim, awa si n s pe m kan tabi meji ti to wa, koda awn ti wn o ni owo gidi lw yoo ni ọmọ kan tabi meji, o waa pọ tan mrin lawn yoo bi ni tawọn, bẹẹ bi wn f obinrin ogun, wn yoo b wn ti kinni kan ko ni ie. r yii ki ie r sin o, bi eeyan ba fi oju sin wo o yoo ina. Looot awn Musulumi lo n fyawo pup ti wn si n bim lonii, ugbọn latij, ati Kristni ati Musulumi lo n e bẹẹ, p awọn ti wn si j oye baba ij ni wn ni ju iyawo kanoṣo l, ti wn si bim to p, nigba ti owo wa lw wn. Bi Yoruba ko ba m gbọn atina ti wn yoo fi pada sidii eto yii, il wa le b kuro lw awn ọmọ wa, tabi awnm tiwn, nitori awn ajoji to lagbara ju wn yoo p ju wn l nilwn.

ni ba si ro pe awn Hausa ti ko mwe lo n bim pup, thun n tan ara r j ni. r mi kan alaye r kan fun mi laipẹ yii, olori awn ologun to gba oye pup ni. O ni oun l si ode kan, oun ba adaj agba ilẹ wa kan tl to ti fyinti, n lawn ba n dapaara, nib loun si ti m fun igba akk pe iyawo mrin lo f, awn mrẹẹrin si paw p wn bi m mtadinlogun, awn m mtadinlogun naa si ti pawpọ, wn ti bi aadta mm fun r oun. Nidii eyi, ni ile oun nikanoo, bi r ba dir idibo, tabir ija, bii grun-un eeyan ni yoo dide latid oun nikan, nitori awn iyawom r i n bim l, bẹẹ lawn mi-in to j obinrin ko ti i bim nile k. Ld tiwa si ree, atim, atim m, gbogbo wn le ma ju mwaa l. Awn ofin oyinbo kan dara gan-an, ugbọn awn kan ko ba aa tiwa ati oril-ede ti a ti ba ara wa mu.

Yoruba gbd ronu lorir iyawoy kan m meji yii, ko ma di pe awnm wa yoo di ajoji nil baba wn. r naa le bi awn obinrin ninu, koda awn olori ij Kristni mi-in le fẹẹ gba a sodi, iyn ni mo e s pe r naa yoo da bii iskus leti. Ṣugbọn ka jokoo ka wo o daadaa, nitori nigba to ba ṣẹl, ti wọn ba le awọn m m wa kuro nil yii, tabi nigba ti awọn ya mi-in ba n jba le wọn lori nilwa yii kan naa, epe taara ni wn yoo maa gbe awn ti wn fa eleyii fun wn ṣẹ lnarun. Emi kan n s ni o, ni to ba ye nikan ni ko da si i.

(49)

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.