Mimiko yoo koju awon oludije yooku loruko egbe ZLP

Spread the love

Gomina ipinle Ondo tele, Dokita Olusegun Mimiko ni egbe oselu Zenith Labour Party panupo yan gege bii asoju won fun idibo aare lodun to n bo.

Nibi ipade egbe naa to waye niluu Abuja lose to koja ni gbogbo omo egbe ti fenuko lati yan Mimiko lai ni alatako kankan.

Leyin ti won yan an wole lo gba awon omo egbe niyanju pe ki won ma se je ki oruko awon egbe nla nla toun fee ba dije deruba won. O ni okan ninu erongba ijoba oun toun ba wole ni bi atunto yoo se ba isejoba Naijiria, leyii ti yoo fun agbegbe kookan lanfaani lati le ni iriri idagbasoke to ye.

Ni ti awon to dije dupo gomina lawon egbe oselu kaakiri

(8)

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.