Lẹ́yìn aroorọda ojo nipinle Eko:

Spread the love

Wọn ri oku akẹẹkọ meji lodo. Adugbo Casso bustop nipinlẹ Eko ni wọn ti ri oku awọn akẹẹkọ naa, ti wọn ko ti mọ orúkọ wọn lasiko ti a n ko iroyin yii jọ.Awọn eeyan n bu ẹnu àtẹ lu awọn obi wọn fun bi wọn ṣe tun jẹ kawọn ọmọ naa o lọ sileewe nigba ti ìjọba kede ana gẹ́gẹ́ bi ọjọ ọlude.

(14)

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.