Ki waa ni Buhari n wa lọ sọhun-un o

Spread the love

Ohun ti wn ni ki okobo b, ko b , o ni oun le ki nnkan soju abr. l ba a ti, o gbe odo nla. Bi wn ba n gunyan lagboole, l ti ko f ikan i e ni yoo sare lọọ gbe odo, odo to ba si tobi ju ni yoo gbe, yoo ni ki awọn le tete pari iṣẹ iyan-gigun naa ni, ugbọn nigba to ba s ọmọ odo naa m iu lẹẹkinni, lẹẹkeji, yoo pariwo, odo yii wuwo ju o, nib ni yoo pari iṣẹ iyan gigun tir si, nitori ko f ikan i e tl ni. Ariwo ti gba gbogbo ilu kan bayii pe Aar Muhammadu Buhari n l si South Afrika, wn ni oun ati olori oril-ede wn lhun-un jọ fẹẹ epade lorir bi wọn ti n pa awọn ọmọ Naijiria, wn ni yoo ba wn lalejo lhun-un, yoo loj di plu wn. Ko si ohun to buru nib rara bi Aar Buhari ba l si South Afrika, ti yoo ba wọn ere, ti yoo si fi s eto ajọṣe to dara mul lhun-un, ugbọn ki i ṣe iru asiko yii. Ki ie iru asiko yii rara. Ki lo n l shun-un lọọ e! e o n lọọ b wn ni, abi o n lọọ ra baba fun wn pe ki wọn ma pa awn m Naijiria m! Bi oun funra r ko ba ṣọra, afaim ki awnmọọta South Afrika yii ma jade lati ho le e, rnaa yoo si di itiju gidi fun oril-ede wa. Bo ba y kinikẹni b ni kan wo, olori ilSouth Afrika lo y ko kk wa silyii, ko waa alaye ohun to ṣẹl, ko si s fun wa  pe iru r ko ni i ṣẹl m. Iyn ni ohun to mu apọnle dani. Tabi bo ba waa di karangida pe kini kan l, minisita lo gbd l, ki i e Aar oril-ede wa. Aal aeju, baba ojo ni; eyi ti Buhari fẹẹ e yii, o tub n fi wa han bii ni ti ko le da nnkan kan e ni. Bi Aar wa yoo ba e ohun to dara, bi wn ti fẹẹ maa ko awọn ọmọ Naijiria kuro lhun-un yii ni iba dara ju, ugbọn gg bii ohun to wa ld tiwa nibi, eleyii naa ko dara, nitori ko si iṣẹ ti wn yoo fun wn e, ko si ibi ti wn yoo fi wn si, wn yoo kan s wn di isansa ati alarinkiri ni, iya ti yoo si j wọn ni Naijiria yoo fr buru ju eyi ti a n ri to n j wn ni South Afrika yii l. Bo ba j ibi ti wn yoo ko wn si wa, ti wọn yoo si maa ri nnkan e ni, ka ko wn kuro lo dara. Am bi ko ba ti i si ibi ti wọn yoo ko wọn si, ki wọn wa nibki wn maa fori ti i, o ee e ki nnkan pada dara. Ko si si ọna kan ti nnkan yoo fi dara ju ki ijọba tiwa pese awn iṣẹ to daa fawọn araalu l, ko kuku si ohun ti awn eeyan yii n wa lsi South Afrika ju iṣẹ aje l. Bi iṣẹ aje ba wa, awn eeyan gidi yoo duro sile, awndaran nikan ni yoo maa rin arinkiri, ohun ti oju wn ba si ri lhun-un, wn ko gbd dele ro fni kan, bi wn si pa wn sib naa, ohun ti oju wọn wa lo ri. Nidii eyi, ohun to yẹ ko j Buhari logun ju ni bi yoo ti pese iṣẹ fawnd wa to fẹẹ sa l kuro loril-ede yii lojoojum, eyi si ti s wa di eeyan ypr nibi gbogbo. Ki Buhari ma tub fi wa wl loju awọn ara South Afrika yii, ko jokoo sile jare, ko si ronu ọna ti iṣẹ oriiiriṣii yoo fi wa ni Naijiria, ti awn ọmọ wa to wa lyin odi yoo fi maa sare pada b nile, nigba ti wn ba gb pe nnkan ti n dara fun awa ti a ko rebi kan.  

(22)

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.