Ki l’Ambọde ṣe fawọn aye to bayii

Spread the love

Awn EFCC l si ile Ambde, gomina ipinl Eko tl, wọn si fẹẹ w ile r lyin r, wn ni awn n wa nnkan kan. Wn ko s pe awn n b o, bẹẹ ni wn ko kwe si kunrin naa, bẹẹ ni wn ko l si ile r to n gbe ni Eko, ile r to wa ni ilu p ni wn l. Wn ni awn n wa awn iwe kan. Awn lọọya ọm p kan ti wn wa nitosi sare kora wn j, ni wọn ba ni awn EFCC naa ko ni i wle onile lyin , awn gbọd j wle hun ni. Wn ni awn eeyan naa gbe apo Ghana-ms-go kan dani, wn ko si jki ẹnikẹni m ohun to wa nib. Awn lọọya naa ni ki wn too wle, afi kiawn ri ohun to wa ninu apo naa, ni wn ba taku wn ni awko le jki wn ri ohun ti awn gbe sinu baagi. Nigbẹyin, awn lọọya yii s pe o eee ko j owo Dla ati awn owo il okeere mi-in lo wa ninu , nigba ti wn ba si ti deb, ti wn wle plu baagi nla naa, wn yoo kede fayepe ohun ti awọn ba nile Ambde ree, awba owo il okeere rptninu ile . Boya oot ni, boya ir, ko sni to le gbẹrii EFCC j, nigba tawn naa ko j ki wn wo ohun ti wn ko sinu baagi ti wn fẹẹ ko wle. Awọnoniroyin beere lwọ Ambde pe e o m pe awn EFCC fẹẹ wa sileoun, o loun ko m, bi wba s foun, ti wn si pe oun ni, oun yoo waa pade wn nibebi ile oun ni. Aweeyan naa wle, wn jade, wni awn ko ri kinni kan, o si daju looot pe awn lọọya to duro si wn lrun ni ko j ki wn kede owo rpt ti wn o ri nile Ambde jade, nitori wn m pe ko si bi awọn yoo ṣe pa iru ir nla bẹẹ nigba ti awn eeyan naa ko kuro lyin wn, gbogbo yara ti wn n w ni wn n ba wn w, gbogboohun ti wn si n gbe ni wn n ri i bi wn ti n gbe e. Ohun ti aweeyan ns nipa ijbyii ree, ati bi awn EFCC yii paapaa e s ara wn diidakuda, ti wn di irinṣẹ eu ti awn oloṣelu n lo bi wọn ti f. Kin ni idilati l sile onile nigba ti ẹ ko s fun onile pe  n b, ki l n wa nib! Kin ni idi lati gbe baagi nla dani l sile onile ti  ko si j ki awọn eeyan mọ ohunto wa ninu baagi! Ki lo de t ko pe onile pko pade yin nibẹ? Iru awnirinkurin ati iwakiwa bayii ni ki i j ki awn araalu gba ileeṣẹ agbofinro yii gb m, nitorpalapala kun w awn naa ojare. Ki lo de to j nikni toba n ba wn ja ninu APC lawn eeyan yii maa n doju ija k, oun ni wn yoo ri i pe o kowo kan j, awn ti wn n fojoojum ko owo j, awn tiwn ti ko owo rpt j wa nib o, wn yoo yi oju wọn sgbẹẹ kan bi r ba tide d tiwn ni. Iynpe Ambde nikan lo kk e gomina Eko, oun nikan si ni EFCC m ọna ile tir, wn o ri awn kan ti wn ko mu owode ile ijọba ti wn si ti di olowo aye, ugbọn to j nitori wn wa ninu APC, ko snikan to le fw kan wn. Eyi ko daa. Yat si pe EFCC n ba orukọ ara wn j, wn n ba orukọ Naijiria j plu, wn yoo si j ki awndaran tub maa pọ si i ni. ebi gbogbo ọdaran lo ti m bayii pe ko si wahalafawn bi awn ba ti le w inu gbẹ APC, ebi wn yoo kan maa kowo j nio ni. lrun yoo kuku daj afeyin-pinran to loun ko j nib, idajlrun n b lori gbogbo oniṣẹ-ibi.

(3)

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.