ipalẹmọ fun ayẹyẹ bi wọn ṣe fẹẹ gbe olomu to waja,

Spread the love

Ni ipalẹmọ fun ayẹyẹ bi wọn ṣe fẹẹ gbe olomu to waja, Ọba Charles Ọladele Ibitoye, atunṣe ti bẹrẹ si aafin Olomu ti Omu-Aran, nijọba ibilẹ Irepọdun, nipinlẹ Kwara. Ọjọ kẹrinla oṣu yii ni wọn fẹẹ ṣẹyẹ ikẹyin f’ori Ade naa.

 

(10)

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.