Ija Azikiwe Pẹlu Sardauna ati Balewa

Spread the love

Awn ohun ti a n ri nil yii lasiko yii, ki ie pe wọn ṣẹṣẹ br, o ti wa ni Naijiria tip, o kan j pe ija naa ti waa n le ju bo ti y lbayii, to si j pe bi awn m Naijiria ko ba mura daadaa funra wn, ibi ti r naa yoo pada b si yoo le ju ohun ti wn ro lkan l. Looot ni inu plọpọ ọm il Hausa ko dun rara pe wn fi jgbn Nnamdi Azikiwe e aar Naijiria, ti wn si n pe e ni Pursidnti, bo tilẹ j pe ipo ifinidigrwu lasan ni, nitori lwAbubakar Tafawa Balewa to j minisita agba, tabi Prime Minister, ni gbogbo agbara ijba igba naa wa. Balewa yii, mọ ẹgb oelu il Hausa, NPC, ni, Sardauna Ahmadu Bello si lolori gb naa. Aṣẹ ti Sardauna ba pa fun Balewa ni yoo tle, bi Azikiwe ba si fun minisita agba yii nimran, bi Sardauna ba ti ni ko gbe oju r sgbẹẹ kan ko ma dahun, o pari niyn.

bafmi Awolw ti ri gbogbo eleyii tl, iyẹn lo e s fun Azikiwe pe ko maa b ki gb oelu toun, iyn AG, ati gboelu tir, iyẹn NCNC, j parapọ, ki awn si jọ ṣejba yii, ki oun j igbakeji r tabi minisita fun eto inawo, ki awn si fi nikni ti awn ba fẹ ṣe pursidnti, ugbọn oun ko e pursidnti ni toun,nitori ko si iṣẹ kankan ti wn n ṣe nib, ipo ijokoo-sile lasan ni. Am bi Azikiwe ba e Prime Minister, ti oun e igbakeji r ati minisita fun eto inawo, gbogbo ohun daadaa ti wn ffun Naijiria ni yoo ee e. Azikiwe ti kk ronu r naa, o si ti gba si Awolw lnu ki awn j ti w b iwe adehun, am lojiji lo yipada biri, igba ti wn yoo si gburoo r, Kaduna ni wn gb pe o wa, o si ti tw b iwe adehun plu Sardauna pe gb oṣelu rati toun ni wn yoo jọ ṣejba, iyẹn naa ni wọn si e fun un ni oye pursidnti.

Pursidnti ti wn fi i j yii lo j koun naa maa lo ipo bii alagbara, nigba to j bawn oyinbo ti wọn gbejba fun wa e n e ld tiwn niyn. Eyi lo bi awn oloelu il Hausa ninu, ti wọn si n foju ajloju-onile wo Zik, wn ni galegale r ti p ju, o si n e bii ni pe oun loun ni Naijiria looot. Nidii eyi, awn aaaju mla yii br si i kun labl, wn si n s fun Sardauna pe ko kil fun Azikiwe ko ti wọ ọm r b aṣọ, garagara r yii ṣẹn p ju. ugbọn Azikiwe paapaa ko tete mọ, afi nigba to br si i ri i ti awn eeyan naa n juko r ranṣẹ soun. Ohun ti wn maa n e ni pe wn yoo e bii ẹni pe awn Ibo lawn n bu, bi wn si ti n bu Ibo ni wn n ko oun naa p m wn, wn yoo si bu u daadaa. Yat si eyi, Azikiwe ri i pe ọp awn ofin ti oun e, tabi awn imran ti oun gbe kal to le tun Naijiria e, Balewa ko tle y kan bayii ninu wn.

Nigba naa ni Azikiwe naa br si i fura, o n wo ayika r, o si ri i pe wn kan fi oun digrwu lasan ni, paapaa lyin ti wn ti gbaagbara oṣelu lw oun, nitori ipo ti oun wa yn, oun ko gbdọ ṣe oṣelu, tabi gbe lyin gb oelu kan tabi ya kan, baba gbogbo Naijiria loun. Inu br si i bi Azikwe, oun naa si n ro o pe gbogbo wahala to wa nil nigba naa, ofin Naijiria lo fa a, ofin naa lo n faaye gba awn Hausa yii lati maae bo ti wu wn soun, ati ni ile ijba. O ti waa ri i pe ki ohunkohun too le yanju, tabi ki wọn too le e ohunkohun ti yoo dara ni Naijiria, afi ki awn tete yaa yi ofin Naijiria pada, ki awọn yi ofin ti awn fi gba ominira pada, ki awọn si e ofin tuntun mi-in ti yoo bagbogbom Naijiria lara mu. O ti kk n sr naa fun awọn ti wn sun mọ ọn, pe awn aie kan wa ninu ofin il wa yii, afi ka tete tun wn e.

Bo ti n sr naa lẹẹkọọkan bayii lo n ta si wn leti ni il Hausa lhun-un, bẹẹ lawn oloṣelu apa ib n s pe ko si ohun to n jbẹẹ, ni ti bi ofin yii ṣe wa ko ba t lrun, ko kuro ni Naijiriafawn, ofin naa ba awn laramu ni tawn. Bẹẹ ofin naa ko dara to, nitori ofin naa fi aaye aegbe, tabi ka-e-bo-ba-ti-wu-wa fawn ara Oke-ya, bẹẹ ni ko si faaye gba awn ti wn j ara Isalya, awn Yoruba ati Ibo, lati e bẹẹ, ofin naa ka wn lw ko rpt ni. Ofin naa fi aaye gba awn Hausa lati maa ni ipin to p ninu awn ohun to j ti gbogbo Naijiria, o si s awn Hausa di baba lori awn nnkan ti ki i ṣe tiwn. O jpe Azikiwe ko ri gbogbo eleyii ninu awn iwe ofin tl, tabi ko j nigba to de ipo lo too ri wn, tabi ko j ipo pataki ti wn gbe fun un lo ti ro pe oun yoo lo lati yi gbogbo nnkan pada. r naa dun un nigba ti kinni naa ja jo o loju.

Azikiwe ti m pe awn Sardauna n tan oun ni, oun si ti ko sinu akolo wn, na kanoo to si wa nilẹ ni lati yi ofin Naijiriapada, ko le faaye gba tru-tm, ki gbogbo eeyan to wa ni Naijria nigba naa si le wa lominira ara wn, ko jẹ nnkan di ni yoo maa kan ijba apap. Ki oun too br si i ronu bayii rara lawn kan ti wn ti ri kinni naa ti n pariwo, wn n spe ko dara, wn n s pe ki wn tun un e, paapaa lati igba ti wn ti ju Awolw swn, ti wn si tun ri i pe bi nnkan ti n l yii, afaimki wn ma waa s Azikiwe funra r swn. Igba yẹn lawn ti n pariwo pe ki wn yi ofin Naijiria pada, nitori bi wn ko ba yi i pada, ọj iwaju oril-ede naa yoo lewu gidigidi ni. Zik ko tete faram wn nibr, am nigba ti oun naa waa ri bi r ti ri gan-an, ati iya ti awn oloelu il Hausa fẹẹ maa fi jẹ ẹ ni ile ijba, oun naa gba pe asiko ti to lati sr lori ofin yii.

N lo ba ṣe bẹẹ lj kan, j naa si jẹ ọjọ ti wn pe e lati waa sr ni yunifasiti nla, iyẹn University of Nigeria, to wa ni Nzuka. Bii ni ti r n gbe ninu tl ni kunrin Pursidnti Naijiria fi rọ ọj naae. O s itan ofin Naijiria, ati bi wọn ti br kinni hun lati ibr pp, ati bi oune ja fun un. e e looot si ni, igba kan wa ninu dun 1946, nigba ti gomina igbanaa, Gomina Richard, gbe ofin tuntun kan jade pe ofin ti wn yoo maa lo fun gbogbo Naijiria ldun naa lhun-un niyn, Azikiwe ni ofin naa ko dara. O ni awn oyinbo ti wn n e ofin naa kan jokoo sibi kan, wn ni awn n ofin fun Naijiria, bẹẹofin ti wn e, ofin to le da wahala sil lj iwaju ni. Lsks ni Azikiwe ti ko awn ni bii ni, eeyan bii eeyan lyin, o di London, ld awn ga ti wn ran awọn oyinbo yii wa si Naijiria, nibi to ti lọọ fi j wn sun nib.

Oun ati awn aaaju gb NCNC ni wn l nigba naa, ninu eyi ti obinrin kan wa ninu wn, obinrin naa si ni Iya Fla, Arabinrin Funmilayọ Ransome Kuti. Ki wn too l, wn alaye gbogbo ofin naa fun Naijiria ati idi ti ko e dara, wn ni looot lawn ko lowo lati l siluu oyinbo, ugbọn bi gbogbo awn m Naijiriaba dide lati ran awọn l, ti wn si fi owo k ran awn lw, awn yoo l. Awn m Naijiria ni ki lawn yoo ṣe, awn Azikiwe ati awn aaaju NCNC, titi dori Herbert Macauly ni awn f ki gbogbo m Naijiria fun awn lowo, ko si iye ti wn fun awn to kere ju, iye ti onikaluku ba ni ni. Bẹẹ ni onitr n da a, onikb n da a, awn eeyan naa si ko plọpọ owo j, owo to le gbe wọn l si ilu oyinbo lati lọọ fj Richard to n e gominasun nib nigba naa, wn ni kawn oyinbo to ran an niṣẹ mọ pe ohun to n e ko dara.

Bo tilẹ j pe ki i ṣe gbogbo ofin naa ni wn pada yipada, awn kan wa nib ti wn yipada, nitori ọr naa ba gomina igba naalru gan-an, o ni Azikiwe ati gb NCNC fẹẹ ba iṣẹ ọw oun jni. ugbọn pataki ohun ti wn ri mu b nib ni pe lati ọj naa lawn oyinbo alaṣẹ ni London ti faṣẹ si i pe wn ko gbd tun e ofin kan ni Naijiria m lai j pe awn m Naijiria fw si i. Ohun to si fa a niyẹn to j looot, lyin ofin ti wn ti e ni 1946 yii, gbogbo awn ofin ti wn yoo tune ti yoo kan gbogbo Naijiria, wọn n ri i pe awn ọmọ Naijiria ti kk da si i, wn fw si i, o si t awn aaaju wn lrun ki wọn too le gbe ofin naa jade. Azikiwe lo e agbatru eto naa, oun lo ko awn mọ ẹgb r j, oun naa lo eto bi wn e fi r naa to gbogbo araalu leti, oun naa lo aaju awọn to n tr owo lw wn, titi ti wn fi relu oyinbo, ti wn si yi ofin naa pada di.    

kunrin naa waa duro si ori pepele ni Nzuka, ninu ou keje, ọdun 1964, o n ran gbogbo ilu leti nibi idanilkọọ to e fun wn ni University of Nzuka, o ni ki wn mọ pe akk k niyi ti oun yoo sr nipa ofin Naijiria, nigba ti ko ba ti dara to, dandan ni ki oun s. O ni bi ofin naae wa nigba naa ko dara, ru to si n ba oun ni pe bi ofin yii ba ṣe bayii wa titi, ti ayipada ko ba ba a ni asiko ti awn wa naa, to ba di lj iwaju, inira ati iynu ti yoo mu dani yoo ti le ju fun awn m Naijiria ti wn ba n e akoso oril-ede naa nigba naa, bi wọn ko ba si fi gbn e e, r naa yoo di wahala gidi gbyin ni. O ni ohun ti oun f ni ki awn ti wn n ejba, awn ti wn n ṣeto ilu lw bayii pe ara wn j, ki wn jokoo yi tabili kan po, kawn naa y ofin Naijiria yii wo, o ni bi wn ba yẹ ẹ wo, wn yoo ri awn ibi ti ko dara nib, wn yoo si le tun un e.

O fr ma si ya kan ni Naijiria ldun 1964 yii ti r naa ko wleti, nitori Zik m alaye i e bi r ba da bayii, o si m ofin oyinbo ti yoo fi gbe r r ls, ati awn ohun ti yoo fi e apẹẹrti r rẹ yoo fi ye ni to n gbọ ọ. r naa ye kaluku daadaa, afi awn oloṣelu il Hausa. e awn oloṣelu il Hausa yii ti n stl pe awn ti wọn n beere fun ayipada ofin Naijiria yii, Azikiwe lo n ti wn lyin, o fẹẹ gba agbara kun agbara, ko le joun ni yoo maa paṣẹ bii Balewa, ki awn Ibo si le le awn ti awn j Hausa danu nile ijba. Wn ni ki Sardauna pe Azikiwe ko ba a sr, bi ko ba si fẹẹ ba a sọ ọ, ko j ki awn lọọ ba a, ki awn si s pe ko jaw ninu iru iwa bẹẹ. Wn ni bi awọn ba l si d r to ba loun ko m nnkan kan nipa r yii, awn yoo ni bo ba j bẹẹ ni, ko s ni gbangba pe oun ko m kinni kan nipa , ko si ni kawn ti wn n sr naa jaw kia.

Eyi ni wn n s labl tl ko too waa di pe Zik l si ibi ayywn ni Nzuka, to si j koko r to s nib ni pe ki wn yi ofin Naijiria pada. N lawn Hausa oloṣelu ti wn ti n sr r tl ba fo soke, wn sare l si d Sardauna, wn ni e r ti awn wi ṣẹ tabi ko ṣẹ, wn niebi ohun ti awn n wi ree, ebi r ti awọnn s gan-an niyn, o a ti pẹ ti awn ti n s pe Azikiwe lo wa lyin awn ti wn n beere fun ofin tuntun, ko si si ohun meji to e n e bẹẹ ju pe ko le gba agbara kun agbara, ko si gbe agbara nla fun awọn ọmọ Ibo, ki wn le s awn ti awn j Hausa di ru wn l. ugbọn kaluku n sọ ọr naa ni abl ni o, wọn ko jsọ ọ sita, wn n bu Azikiwe ninu ile, ko sni kan to to bẹẹ lati sọ ọr naa jade si gbangba. Afi iweiroyin kan ti wn ni nigba naa, iyẹn Citizen. Iyẹn naa lo gba ọr awn oloelu ilẹ Hausa yii s.

Bo til j pe iweiroyin Citizen lati il Hausa yii ko darukAzikiwe, ko sni ti yoo ka a ti ko ni i m pe Nnamdi Azikiwe ni wn n fi r naa ba wi. Iwe naa ni o p ti oun ti n woye awọnkan ti wn fẹẹ da Naijiria ru, ti wn n s pe ki wn yi ofin Naijiria pada lo dara. O ni awn ya naa ko lero meji lọkan ju pewn fẹẹ fi awọn kan e ru awn mi-in l, awọn fẹẹ jẹ ọga, ki wn si wa awn ti wọn yoo maa iṣẹ fun wn, iyẹn ni wn e n beere fun ayipada ofin. Citizen ni gbogbo ko til dun oun bii ti agbalagba kan ti eeyan ko lero pe yoo maa ṣe iru r, agbalagbato y ko tun ilu e to jẹ oun gan-an lo fẹẹ ba a j, ni ti wn fi si ipo nla ti ipo naa ko j loju, to jẹ ọna lati di ga gbogbo aye lo n ba kiri. Wn ni alaimoore ni iru ni bẹẹ, bo ba si mọ pe ipo nla ti awn gbe oun si ko tẹ oun lrun, ko fi ipo naa sil fun awn to ni nnkan wn.

Iwe Citizen yii ni, lrun funra r lo fi awn Hausae olori Naijiria, lrun lo fun wn ni oril-ede naa gg bii tiwn, ko si si ohun ti ẹnikni le e si i, tawọn Hausa yii ni Naijiria yoo maa j titi lae, bi awọn ba si e f lawn yoo e dari oril-ede naa. O ni ikoriira ati ilara lo n mu awọn ti wọn n binu ijba awn Hausa e ohun ti wn ne, nitori oun ti woye titi, oun si ti ka ofin naa ni akatunka, oun ko ri kinni kan ti ko dara ninu ofin Naijiria, awn Ibo ti wn si n sare kiri lori ọr yii kan fẹẹ da wahala silni. Am bi awọn ọmde Ibo ti wn n sare kiri yii ko ba m itan, awn baba wn to m itan y ki wn pa a fun wn, ki wn si alaye idi ti Hausa fi n e olori Naijiria fun wn. Tabi wn ko ri i pe awn lawpọ ju ni, e wọn ko ri i pe awn lawn ni oril-ede awn ni, nigba ti awn ti le p ju awn to ku l yii, ti awọn si ni il to pju tiwn l, awn naa lawn yoo maae olori.

Ki agbalagba Ibo to m itan, to si m bi r ti ri ma ba wn da si iru nnkan bayii m, ko lo ipo agba r lati fi tun nnkan e ni, nitori agbalagba to ba wa nibi kan ti ib ba baj, thun ki i ṣe agbalagba daadaa, agbalagba ẹlyamya, agba buruku lasan ni.

Awọn ọr buruku, ati owe ibanuj ti iweiroyin Citizen s ranṣẹsi Azikiwe ninu ou keje, ọdun 1964 yii ree, r naa si ka Azikiwe lara. ugbọn ọr naa ko dun Azikiwe to awn agbaagba ilẹ Ibo, nitori bẹẹ loe j iwe iroyin tiwn naa kan, iwe Outlook ni wn ni ko da Citizen lohun, M.C. K. Ajuluchukwu ni wn si fi r naa ran, eyi lr buruku toun naa s ranṣẹ si awn agbaagba il Hausa:

maa ka a l ls to n b.

(40)

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.