Fulani dana sun oko koko niluu Igangan

Spread the love

Oko koko eeka bii mẹẹẹdogun lawn afurasi Fulani darandaran dana sun niluu Igangan, nijba ibil Ariwa Ibarapa,l’Ọjruu, Wẹsidee, ọs to kja.
gbni Gbenga Oketoyan jko di mim pe lj keje,
ou kin-in-ni, ọdun yii, lakooko toun wa sinu oko loun akiyesi pe gbogbo awn ohun gbin bii paki, iu ati kaṣu toun gbin ni awn Fulani ti bajẹ, toun si ti lọọ fr naa to tean lpaa leti ugbn ti won ko gbe igbes kankan lori rẹ.
        O tsiwaju pe lj keji toun l sinu abule toun ko awn ounj, oogun afinko ati alupupu Jicheng, atawn nkan mi-in towo r j milinu kan Naira, ati oko koko lawn Fulani naa dana sun raurau. Onarebu Peter Gbadegẹṣin jdokun, ti abule jdokun, lagbegbe Bogunmbẹ, naa sọ pe awn Fulani ba nnkan oko oun towo rẹ to bii ilaji milionu Naira jẹ, ti gbni mniyi Ṣẹgun, olukni nileewe C/S Igangan, naa loun ti padanu owo to to bii milinu kan Naira latari aklu awn
Fulani.
 ga lpaa agbegbe naa, Ọgbni Lateef Babatunde Akanbi,lasiko to n fidi iṣẹl naa mul fakroyin wa lakooko ta a pe esori foonu r latari sun ti wn fi kan an pe o n gbe lyin awn Fulani, jko di mim pe gbogbo awn afurasi lọw agbofinro ti t, ti wn si ti ko wn lsiluu Ibadan fun iwadii.
        Seriki Fulani ipinlẹ Ọy, Oloye Salisu Kadiri, ninu r r
sọ pe ki i e gbogbo sun ti wn fi kan awn Fulani lo joot, o ṣalaye pe gbogbo sun to ba ni i e plu wahala laarin
agb ati Fulani loun yoo mojuto, o ni iṣẹ ti ijba ipinlẹ Ọy gbe le oun lw niyn.

(28)

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.