Eyi ni awon ti yoo soju egbe oselu kokokan ninu idibo odun to n bo ni Kwara Stephen Ajagbe Ilọrin

Spread the love

Abdulrahman Garba                Accord

Kwara North

Abubakar Mohammed           PDP

Sadiq Suleiman Umar            APC

Aliu Bello Yamman                 LP

 

Samuel Saba John                 SDP

Ganiyu Jaiyeọla Ọmọtọshọ   Accord Ọjọ Aiku, Sannde ọsẹ yii, ni ajọ INEC kede pe ipolongo bẹrẹ fun awọn oludije ti yoo kopa ninu idibo aarẹ ati ile igbimọ aṣofin. Ọjọ kin-in-ni, oṣu kejila, ni awọn to maa dije funpo gomina ati ile igbimọ aṣofin ipinlẹ yoo bẹrẹ ipolongo wọn.

Ọsẹ to kọja lọhun-un lajọ eleto idibo, INEC, gbe orukọ awọn oludije fun ipo gomina mejilelọgbọn ti wọn yoo dije ninu eto idibo ọdun to n bọ nipinlẹ Kwara jade.

Lara awọn oludije naa ni awọn obinrin mẹta wa: Muibi Muibat Aduke, tẹgbẹ oṣelu APA, Diakoni Comfort Yinka, to n ṣoju UPP ati Rukayat Toyin Tijani, ti ẹgbẹ MPN.

Awọn oludije yooku funpo gomina ati ẹgbẹ oṣelu wọn ni:

Rasak Atunwa                      PDP

Abdulrahman AbdulRasaq  APC

Issa Arẹmu                             LP

Ọlajide Adebọla                     SDP

Ayọrinde Adedoyin                Accord

Diẹ lara awọn ti yoo dije funpo Sẹnetọ ni:

 

Aarin gbungbun Kwara

Abubakar Bukọla Saraki       PDP

Ibrahim Yahaya Oloriẹgbẹ    APC

Abdulsalam Kuburat              LP

Babatunde Sulyman               SDP

 

 

Guusu Kwara

Abdulfatah Ahmed                 PDP

Lọla Ashiru                              APC

Awọn to ku lawọn oludije fun ipo ile igbimọ aṣoju-ṣofin ati ile igbimọ aṣofin ipinlẹ.

Ọjọ kẹrindinlogun, oṣu keji, ọdun to n bọ, lajọ INEC ni idibo aarẹ ati ti ile-igbimọ aṣofin agba yoo waye. Ọjọ keji, oṣu kẹta, ni eto idibo gomina atawọn ile igbimọ aṣofin ipinlẹ yoo waye.

(4)

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.