Eleyii ki i ṣe ibo, oju ogun gidi ni

Spread the love

Bẹẹ awn ti wn n ejba wa ni ko e daadaa, r buruku to n run leti kun nu wn. Wn ni olori gbẹ oṣelu APC sọ pe bi awn ba riigi ibo, iyẹn ti awn ba ṣojooro ibo lati tun ohun ti PDP bajẹ ṣe, iyẹn ki i ṣe ẹṣẹ. Bi eeyan ba n gbọ ọr lnu iru awn Oshiomhole yii, oluwar yoo i r s, nitori lara awn eeyan raurau, eeyan kukuru biliisi,bayej to n pe ara r ni atunluue loun naa wa, awn ni-ibi to n pn m re baluwni gbogbo wn. Nibi yoowu, ohun yoowu ko si de, ojooro ko dara, eru ko dara, ninu ijba dmokiresi, ohun ti araalu ba flo gbdọ ṣẹ. Bi araalu ba sọ pe dindinrin lawn f ko ṣejọba awn, ti wn si dibo fun un, to j ibo ti wn di lawn to n eto ibo naa ka ti wn si dibo fun dindinrin, ko sohun to kan nikni, nigba ti dindinrin ba si br si iejba wn, awn naa yoo ri i pe aie lawn e, bo ba digba mi-in wn yoo dibo wn flgbn. Koda ko j ole ni wn dibo fun, awn ti wn n ṣeto idibo ko gbd yi i, ofin dmokiresi ni pe ohun ti araalu ba f, ti wn dibo fun, lawn ti wn ba fẹẹ ṣejba gbd tle. Ohun ti awn Oshiomhole f naa lo ṣẹl yii, ti wn dibo ni awn ipinl kan ni Naijiria to da bii pe ogun ni wn n ja nib, ti wn ko ṣọja l, ti awn lpaa ko si niye. Awn ibi ti wn ko awn lọpaa l yii, ati awọn ṣọja, ki i ṣe pe awn yii n mojuto awn ti wn fẹẹ da ibo ru tabi ji apoti ibo o, kaka bẹẹ, awn gan-an ni wn n ran awn ti wn ba fẹẹ ji apoti ibo lw, ti wn n ba wn gbe e, ti wn si n gbowo lw awọnoloṣelu to ran wn. Nibi ti wọn ba ti ri i pe ero p ti wn n dibo fni kan ti awọn ko f, wn yoo da ibo ibẹ ru, wn yoomu ni ti ko yẹ ki wn mu, wn yoo si maa yinbọn soke laulau. Ọpọ awn eeyan ni wọn pa nitori r ibo to kja l yii, o si jẹ nnkan ibanuj pe nibi ti Naijiria loruk de, ti a si laju de yii, awn eeyan yoo i maa yinbn pa ara wn nitori ọr ibo. O buru gan-an ni o. Nigba ti ki i se pe a n ba ara wa jagun, ti ki i e pe oju ogun la wa, ti ki i si i e ran lati e olori ilu wa, ti a oo waa tori ibo didi ko ṣọja sita, ti a oo ko lọpaa adigboluja, ti wn yoo si maa yinbọn paayan, ti a oo si s pe ijba dmokiresi la n e. Eleyii ki i ṣe ibo didi, ogun jija ni, iwa ika si ni plu. j kan n b ti araalu yoo beere lw awn to n pa wn lm yii plu awọn to ran wn idi ti wn fi n pa wn lm. j naa ko ni i rgb fun wn, nitori jọ ẹsan ni yoo j, j aburu ni fun wn.  Ki gbogbo araalu fkan bal, jọ kan n b ti lrun yoo gbọ adura wa. A oo b lw awn onibaj yii, nitori Ọlrun yoo de wn ni ṣẹkẹṣẹk lw ati lssibi kan ni.

(30)

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.