EFCC gbẹsẹ le biliọnu meji to je ti oga ologun tele Onidaajọ

Spread the love

Mojisọla Ọlatoregun ti ile-ẹjọ giga ijọba apapọ to wa ni Ikoyi, niluu Eko, ti paṣẹ l’Ọjọruu, Wẹsidee, ọsẹ to kọja, pe ki biliọnu meji o le (N 2, 244,500,000), ti wọn gba lọwọ ẹni to ti figba kan jẹ ọga awọn ọmọ ogun oju ofuruufu lorileede yii, Ọgagun-fẹyinti Adeṣọla Amosu, di ti ijọba apapọ.

Adajọ tun sọ pe ki ajọ EFCC ṣe agbejade idajọ yii fun araye ri, ki ẹni to lowo naa si ṣalaye idi ti ko fi yẹ ki ijọba apapọ gbẹsẹ le e. O ni awọn ẹri ti ajọ naa ko kalẹ fi han pe ọna ti Amosu gba ri owo naa ko mọ rara.

Bẹẹ ni miliọnu kan o le ọgọrun-un Naira ti iwadii tun fi han pe ileeṣẹ kan ti wọn n pe ni Solomon Enterprises, lo ni in, ṣugbọn iwadii ajọ naa fi han pe Amosu lo ni in, o si ti di ti ijọba apapọ.

 

(6)

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.