Eepinni meji, ọgbọọgba ni

Spread the love

Laye atijko ti i pnaa o, ko too di pe Naijiria br si i na owo Naira yii ni, owo kan wa ti wn n pe ni eepinni. Ede oyinbo ni wọn yi, nitori ‘hef-Peni’ (half penny) ti awn oyinbo n pe owo naa, to si nira fun awn eeyan tiwa ni wne da kinni hun si awuruju, eepinni ni eepinni n j ojare. Owo naa j idaji pni, tabi idaji owo ti a n pe ni kb yii, o kere ju kb l. ugbọn ohun to maa n ya awn baba wa ati iya wa lnu nigba naa ni pe bi wọn ba mu eepinni kan dani, ti wn tun mu omi-in sibomi-in, tabi tilomiiran tun mu tir dani, bakan naa ni yoo e ri. Iyn ni wọn e n fi i sr nigba naa pe eepinni meji, gbọọgba, tabi kan naa ni. Boe ri fun Aar wa yii, o fr j pe bẹẹ naa lo ri fun Gomina ipinl Katsina, Alaaji Bello Masari. Bi adanwo ba ba ni kan ju lasiko yii, o fr j Bello Masari ni. Adanwo naa si ni pe oun ni gomina ipinlti Aar Muhammadu Buhari ti wa, iyn Katsina. Ipinl yii naa waa ni awn janduku ti pọ si jul, iye mi to si tiofo nib laye Buhari yii, tirela kan o le ko o l, afi bo ba j reluwee. Nigba ti Masari wa gbogbo ohun ti yoo e ti, o kk ba awọn janduku naa epade ls to l lhun-un, o lọọ ba wọn ninu igbo, awn yn si gbe ibn ti i laya, nibẹ ni wn ti j s gbogbo ohun ti wn fẹẹ s. Lyin to ba olori awn janduku sr tan, o kri si oril-ede Nijee, o ni nib ni wn ti wa, oun gbd lọọ ri awn olori wn nib, ki oun s fun wọn pe awnm wn to ne janduku wa ld awn o, bawo lawọn yooe e e si. r naa ko yat si bii igba ti eeyan n pariwo, to n ranju, to n ffun foo, to n lgun too, niwaju odi, yoo kan e ara r lee ni, nitori bi ko ba ni j riru, ak fri yoo gbe e. Tabi ti eeyan ba waṣọ alarabara, to waa ko awn afju j pe ki wọn waa woran oun. Oore kin ni iru iyn yoo ṣe fnikni. Ṣẹ ka s pe goimna tiwa ko gbni abi ko mran, abi kin ni iṣẹ awọn oludamran ti wn ko j. ijọba Nijee lo ran awn ọmọ wn jade ki wn maa lọọ e janduku ni, abi wn dagbere fun wọn pe awn n l si Naijiria lọọ maa ba wn gbe nibẹ, tabi wn m idile ti wn ti wa ni Nijee ni! Ohun ti wn f ki awọn ti wn n ejba Nijee e sir to wa nilẹ yii ko ye nikan. Awn ọmọ ti wn ko nile, ti wn ko ni adirẹẹsi, ti wn ko m nikan ni oril-ede ti wn ti wa, ti awn ara ib naa ko si m wn, ki waa ni ijọba ib le e fun wn. Nigba ti adigunjale ba n paara ile eeyan kan lojoojum, to n waa ko o lru l, ti onile ko si ri ohun meji ti yoo e ju ko maa lọọ ba adigunjale naa sr, kin ni yoo maa waa wi fun un. e ko ni Satide nikan ni ko maa waa jale, ko ma wa ni Sannde ni, tabi ko  ni to ba waa jale, ole lasan ni ko ja, ko ma ba iyawo oun sun! i! Iran janduku kan, tabi adigunjale kan, ki i fi ibi ti wọn ba ti n jale ti wn n ri e sil, wn yoo wa nib, ti wn yoo maae oogun m oogun, ti wn yoo maa ra ibn m ibn, titi ti wn yoo fi j awn eeyan ti wn ba wa nib run ni. Bi wn ba j wn ru nibi kan, wn yoo tun kja sibomi-in, wn n ba iṣẹ wn l niyn. Epe ni wn fi n wo epe, oju br ko si ee gba ọmọ lw ekur. Bi janduku ba w ile eeyan kan wa, awn d adugbo, tabi awọn ologun leeyan yoo fi le wn l. Bi ijọba Buhari ba dari awn ṣọja si agbegbe ti awọn janduku yii wa, wn yoo le wn l kia, koda, wn yoo kja oril-ede Nijee ti wn ni wọn ti wa yii. Ṣugbọn ohun to n e awn naa wa lara wn, boya wn ro pe Fulani ni wn, ọmọ iya kan naa lawọn, ko y ki awn le wọn bẹẹ, ko y ki awọn pa wọn bẹẹ. Ṣugbọn awn n pa awn m tiyin, wn n ji wn lru ko lọ, wn n fipa ba awn obinrin wn sun, si n foju mọọya kan naa wo wn, ebi ara yin l n e. s fun Buhari ko ko awn ṣọja sibẹ, gbogbo arinkiri yii ko ni i mu nnkan kan wa o.

(16)

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.