BUHARI TI GBOWO JADE: BILIỌNU KAN OWO DỌLA LO FẸẸ FI RA OHUN-IJA NITORI BOKO HARAM!

Spread the love

Aarẹ Buhari ti buwọlu biliọnu kan naira dọla fun rira ohun ija fun awọn ọmọ ogun lati fi gbena woju awọn iko Boko Haram. Minisita fun eto aabo, Mansur Dan-Ali lo sọ eleyii di mimọ lẹyin ipade eto aabo ti wọn ṣe, eyi ti Aarẹ Buhari dari rẹ.

(14)

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.