Bo ṣe daa niyẹn … ṣugbọn kan naa lo wa nibẹ

Spread the love

Bi eeyan ba ri ohun to n ṣẹl ni awn ile ijba wa lasiko yii, kan onithun yoo maa bal pe o da bii pe awn ijọba yii fẹẹ tọ ọna to dara, awọn oloṣelu kọọkan ti wn ko myat laarin oṣelu ati ijọba ie yoo ys to ba ya. ugbọn awọn ohun to n ṣẹl, ati bi awn eeyan naa e n eto ijọba wn fihan pe nnkan yoo dara fun wa bo ba n ba bayii l. Sanwo-Olu, gomina ipinl Eko, ra mto marundinlaaadoje (125), o fikada marundinlogoji (35) ti i nidii, o ko o fawọn lpaa ati awn agbofinro to ku, o ni ki wọn pin kinni naa laarin ara wn, fun eto aabo to peye ni gbogbo ipinl r. Bi oun ti n ko tir fun wn, bẹẹ naa ni Dap Abidun ti ipinl Ogun naa ko grun-un mto, ati grun-un meji kada nla fawnlpaad tir naa, o ni ki awn naa fi maaeto aabo to peye. Ko si ohun ti eeyan le e ju ka ki awn gomina wnyi l, paapaa lasiko ti ko sowo lw ijọba pup, to si j wọn ṣẹṣẹ tun de ile ijba ni. ugbọn wn m inira awn eeyan, wn si ri ibru ati ifoya wọn pe nnkan ko dara. Bi awọn lpaa ba fẹẹ ja, ti wn ko ba ni irin iṣẹ nk, ebi awndaran ati awn ajinigbe to wa niluu yii yoo kan maa tobi si i ni, ti wn yoo si maa ba iṣẹ aburu wọn l. ugbọn bi irinṣẹ gidi ba wa, ti mto to le sare daadaa wa, ko si ohun to yara ran awn lpaa wa lw ju bẹẹ l. Ṣugbn kan to wa nibẹ ni pe e awnlọpaa s pe awn kinni yii lo n j awọn niya, e wn sfun wn pe nitori ti ko si mto lawn koe iṣẹ awn. Bi wn ba sbẹẹ, r naa yoo dara bi awn gomina yii e e yii. ugbọn ti wn ko ba s bẹẹ fun wn, to j awọn idi mi-in lo n di wn lw, to j boya ariwo ti awn eeyan n pa pe awn ara Abuja lo n paṣẹ pe ki wn ma mu Fulani, ki wọn ma fiya j Hausa fun wn, koda nigba ti wọn ba ba wn nidii iwadaran, aa j pe ki i e iya mto lo n j wn niyn, bi eeyan ba si fi gbogbo aye yii ra mto fun wn, awn araalu ti wn n rin jẹẹj wọn laago meje aab si mj al lawn lpaa yoo maa a kiri lati gba owo lw wn, ti wn yoo ni awn mu wọn nibi ti wn ti n rin irin-oru. Nitori loe j ki ie mto nikan lawọn gomina yii yoo ra, tabi iru awn inawo yii nikan ni wọn yoo maa e, wọn gbd maa pe awn olori lpaa adugbo wnyi si kr, ki wn j sr, ki wn si m ohun to n ṣẹl looot, iyẹn ni wn yoo fi le m na ti wn yoo gba lati koju ioro to ba wa. Eyi ti wọn e yii daa o, ki i pe ko dara, o tildaa gan-an ni. Bo ba j awnlpaa naa lo n gbabde, gbogbo aye yoo ri wn bayii, wn yoo m pe ki i ṣe awn gomina ni ko da si ioro wn. lrun yoo kuku mu alaafia ba wa nil Yoruba, ogun ajinigbe ko ni i ko wa l.

(28)

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.