Bi wahala awọn ọmọ Yoruba ati Ibo ti wọn fẹẹ wọ iṣẹ ṣọja ṣe bẹrẹ ree, laye ijọba awọn Ọbasanjọ

Spread the love

Ni oni yii ni oril-ede Naijiria, awn ti wn jẹ ẹya Hausa-Fulani ni wn p ju ninu iṣẹ ologun, paapaa awn ti wn wa lati Sokoto, Kano, Katsina, Zaria, Kebbi titi de Zamfara. Lara ohun to si n fa wahala titi di oni ni oril-ede wa niyi o. Bẹẹ kinni yii ko ri bẹẹ tl. Nibr pp, awn ara Benue, Plateau atawn Bornu ni wn p ninu iṣẹ ṣọja yii, awn ti wn si jẹ ọga ninu iṣẹologun yii ni awn Yoruba atawn Ibo. Awn ara ipinl Kogi, Niger, Benue, Plateau titi de Taraba ati Gombe, awn yii ni wn p jul ninu iṣẹ naa, awn ni ṣọja to n jagun, puruntu lawn, awn Ibo ati Yoruba si lga nib titi di bii ọdun 1961. ugbọn laye awn basanj, nibi ipade apero ofin ti wn e ni 1977 si 1978, nib ni wn ti fi ontẹ lu u, ti wn e ofin to s awn ṣọja di ga ninu iṣẹ ologun, to si j awn naa tun ni puruntu to p, iṣẹ ṣọja naa si da bii pe tiwn ni.

Ni ibẹrẹ pp, nigba ti awn oyinbo da iṣẹ ṣọja yii sil, Lokoja ni wn ti da a sil ni 1898, awn m ogun Ibadan, ati awn m ogun Agatu ati Garra ni adugbo ti a n pe ni Kogi bayii plu awn Kanuri ajagunjun lati Borno lo si p jul ninu awọn ti wn kkọ ṣe ṣọja naa. Lati igba yii lo ti j awọn ti wn ba wa lati adugbo Kogi, Benue Plateau ati Niger, awn ni wn pọ ju ninu iṣẹ ṣọja, awn ni wn n jagun. Awn yii lawn oyinbo lo lati fi gba gbogbo il Hausa to ku, lati Kano titi lọọ de Sokoto. Awn ni wn koju awn m ogun Hausa ti awn ba agbegbe naa maa n lo, loju s ni wn si ti ṣẹgun wn plu agbara ibn ati im nipa ogun jija tawn oyinbo yii ti k wn. Lyin ti wn ti gba il Hausa yii, ti Naijiria si ti gba ominira ni awn mọ ilẹHausa lati agbegbe Kano, Sokoto ati Borno br si i w inu iṣẹnaa, ugbn puruntu ni wn, nitori wn ko kawe rara.

 

Awn Ibo ti wn kawe di, tabi ti wn ba awn oyinbo iṣẹ ni wn kọkọ br si i di ga ologun. Bii apẹẹr, nibr aye Aguiyi Ironsi, oyinbo kan lo n ba ṣiṣẹ bii ọmọ ọd lasan, oyinbo naa lo si eto iwe mfa r, iwe mfa yii ni Ironsi si ba w iṣẹ ologun ni 1942, ugbọn ki oun too deb, kunrin kan ti kawe mfa to ti kk w iṣẹ naa, Wellignton Bassey loruk r, dun 1936 lo si w iṣẹ ologun. kunrin Bassey yii si ni m Naijiria akk ti yoo kuro ni ipo puruntu, ti yoo di fisa ninu iṣẹ ṣọja, lati dun 1948 lo si ti di kaputeeni ninu iṣẹ ṣọja ni Naijiria, oun naa si ni kaputeeni akk ti wn kk ni ninu iṣẹ ologun, iyẹn kaputeeni ni yoo jẹ ọm Naijiria tiwa. Ibo ni wn n pe e, bo til jẹ pe adugbo ti a n pe ni Naija Delta bayii lo ti wa. Lyin tir ni rnaa kan Aguiyi Ironsi, ni ta a sọ pe o w iṣẹ ṣọja ni 1942.

dun 1951 ni wn fi oun naae kaputeeni, iyẹn ninu ou kwaa, ọdun naa. ugbnni kan wa ti wn j w iṣẹ ṣọja ldun kan naa, m Yoruba loun, Samuel Ademulegun lorukọ tir, dun 1951 yii kan naa ni wn s oun naa di kaputeeni, ninu ou kejila, ọdun naa ni, iyn ni pe ou mta pere ni Ironsi fi ju u l nipo ga awn ṣọja. Babafmi Ogundipẹ naa w iṣẹ ṣọja yii ni 1942, ugbọn titi di dun 1951, ipo lfutenanti loun wa, ko ti i di kaputeeni rara. dun 1943 ni Adekunle Fajuyi w inu ṣọja, ṣugbọn ldun 1952 loun naa ṣẹṣẹ di lfutenanti, bẹẹ ni ko ti i sun m kaputeeni rara. Bakan naa lo ri fun Ralph odinde toun naa wọ ṣọja ni 1943, lfutenanti loun naa wa ni 1952 yii. Bo til jpe Fajuyi ti aaju r de ipo naa, dun kan naa ni wn j di lfutenanti. Ni 1948 ni Adeyinka Adebay wọ ṣọja, ṣugbn nigba ti yoo fi di 1953, oun naa ti di lfutenanti.

       

Conrad  Nwawo lati il Ibo lm ikyin wn lenjelenje, ldun 1950 loun naa w iṣẹ ologun, bo si til j pe asiko to wọṣẹ naa ree, laarindun mrin, iyẹn ni 1954 lo ti di lfutenanti, nitori oun kawe giga ko too wọṣẹ ologun. Asiko yii naa ni, ni dun 1950 yii naa, ni awn m Hausa mrin kan de saarin wn. Kanuri lawn mrẹẹrin, nitori iran jagunjagun lawn n e. Zak Maimalari ati Umar Lawan ti wn j wọ ṣọja ni 1950, Kur Muhammed ati Abome Largema ti wn j wọ ṣọja ni 1951. Lawan fi iṣẹ ṣọja silẹ, o loun ko e m, am Maimalari, Kur Muhammed ati Largema di lfutenanti lọdun 1956. ni kan wa to jẹ ọm ikyin wn, Pam loun n j, oun ni ga ṣọja akk lati Benue-Plateau, ni Jos, lo ti wa, bo til j Kaduna ni wọn ti bi i. Oun ko ti i di lfutenanti, igbakeji lfutenanti loun wa ni dun 1956.

Ohun ti eleyii tum si ni pe titi di dun 1956, ko si ọga ṣọja ti wn n pe ni kaputeeni lati il Hausa. Awn kaputeeni mrin naa lo wa, awn mrẹẹrin si ni Bassey, Ironsi, Ademulegun ati odinde, awn ga pata ninu iṣẹ ṣọja ti a ni ni Naijiria niyn. ugbn nigba ti yoo fi di dun 1960, iyẹn ninu ou kwaa ti Naijiria gba ominira gan-an, awn ga ṣọja naa ti pọ si i, nitori ọplọpọ awn m Ibo ti wn kawe mwaa jade ti r w inu iṣẹ ṣọja, wn si ti pọ ju awọn to ku l. e a ti s tl pe awn Yoruba ko fẹ ọm wn ninu iṣẹ ṣọja, nitori iṣẹ ipanle, iṣẹ ti ki i e iṣẹ ọmluabi ni wn ka a si, iṣẹ alakwe gidi lawn f fun awn m wn. Bẹẹ naa lawn Hausa ko ti i maa kawe, wn ko si ni awn oniwee mwaa to p ld wn debii pe wn yoo rwn sinu iṣẹ ṣọja, nitori bẹẹ lo e j awn ga to wa lati dtiwn naa ko p rara.

ugbn ni ti awn Ibo yii, awn p jaburata ni, awn fisa, iyn awn ga ti wn si ti il Ibo jade nigba ti Naijiria n gba ominira yii j mejidinlogoji (38), awn yii ni Duke Bassey, Aguiyi Ironsi, David Ejoor, Conrad Nwawo, Hilary Njokwu, Umeh Ogere Imo, Eyo Ekpo, Gabriel Okonweze, Festus Akagha, Donatus Okafor, David. O. Okafor,  Israel. C. Okoro, J. J. Brown, E. Ekanem, Rudolf Trimell, Phillip Effiong, David Ogunnewe, B. O. Adigio, Mike Ivenso, Ben Ochie, George Kurobo, Alex Madiebo, Michael Okwechime, Macauley Nzefili, Ben Nwajei, Alphonsus Keshi, Chukuemeka Kaduna Nzeogwu, Patrick Anwuna, Arthur Unegbe, Roland Ogbonna, Antony Eze, Ezeugbana, Christian Ude, Chude Sokei, Emeka Odumegwu Ojukwu, Patrick Amadi,  Henry Igboba, Ifeanyi Aniebo. Ohun ti eyi tum si ni pe ni Naijiria lj kin-in-ni, ou kwaa, ọdun 1960, nigba ti a ba da awn fisa inu iṣẹ ologun si na grun-un, ik marundinlaaadrin (65%), lawn mIbo yii n e.

Ni ti il Yoruba, awn fisa mwaa pere la ni. Awn yii naa ni Sam Ademulegun, Ralph odinde, Babafmi Ogundip, Francis Adekunle Fajuyi, Robert Adeyinka Adebay, Victor Banj, James Olutoye, Emannuel otomi ati Oluṣẹgun basanj. Ni ti awn fisa lati il Yoruba yii, bi a ba da gbogbo awn fisa ti Naijiria ni ni j kin-in-ni, ou kwaa, 1960, si na grun-un, mtadinlogun ataab (17.5%), pere ni ti awn ologun lati il Yoruba, ko ju bẹẹ l.

Ni ti awn ara ilẹ Hausa, fisa mj pere lawn ni ninu iṣẹologun. Awn yii ni Zak Maimalari, Kur Muhammed, Abogo Largema, James Pam, Yakubu Gowon, Hassan Katsina, Joe Akahan ati Abba Kyari. Eyi j pe ni j kin-in-ni, ou kwaa, ọdun 1960, bi a ba da awn fisa ti wn wa ninu iṣẹ ṣọja ni Naijiria si nagrun-un, mrinla pere (14%) ni awn Hausa.

Ohun to fa a ti eyi fi ri bẹẹ ni pe titi di dun 1960 yii, awn oyinbo ni wọn n ejba, bo si til j pe awn fran awn ya Hausa ju awọn to ku l, sibẹ, awn kinni kan wa ti wn ko e. ni to ba fẹẹ w iṣẹ ṣọja yoo e idanwo, wn yoo y  wo daadaa, thun yoo si paasi gbogbo awn idanwo to ba e, bi ko ba ti yege, ko sni ti yoo mu un. Ohun to fa a ti gbogbo awọn nnkan naa fi ri bo e ri ree. Awn mkunrin lati il Hausa yii ko tete ja gbn iwe rara, awn ti wn si aaju ninu wn lati kawe nigba naa ni Maimalari, Kur Muhammed ati Largema, lati Borno lawn ti wa, ugbọn wn gbe ni Kaduna, o si rrun fun wn lati tete ri ileewe w, nitori Kaduna ki i e ilu ni kan ni ilHausa, awn oyinbo ni wn da a sil, lara ohun ti wn si kkọ ṣeto sib ni ileewe, o si di dandan kawn m to wa nib lsileewe, paapaa awn ti baba wn sun m ijba.

Ileewe to kk gbayi ni il Hausa yii naa ni Kaduna College ni Zaria, bi a ba si ranti pe awn ara Zaria ni wn ni il Kaduna, r naa yoo ye eeyan daadaa, pe bi mọ kan ba wa ni Kaduna to fẹẹ kawe giga, Zaria yii ni yoo l. Awn oyinbo ni wn da a sil, idi ti wọn si e da a sil naa ni ki awn m Hausa to ba fran lati kawe le l si ileewe giga nib. Looot lawn oyinbo ti ba Ahmadu Bello srpe ko j ki awn m wn maa w iṣẹologun, ko ko awn m il Hausa sinu iṣẹ naa, sib wọn ko tori iyn yi eto naa pada, pe m to ba fẹẹ l sileewe yoo kawe, yoo si mọ ọn, bẹẹ ni yoo lọọ kawe si i ni Ghana, tabi ni ilu oyinbo, ko too le di ga ninu iṣẹ ologun. Nibi yii ni rnaa ti di ioro funp awn m Hausa, nitori pup ninu wn ki i gbna ileewe kja rara, bi wn ba si w iṣẹ ṣọja, puruntu ni wn yoo wa nib, nigba ti won ko mwe kankan.

Amọ nnkan yat pata lyin ti Naijiria ti gba ominira yii, nigba naa lo si di pe awn fisa lati il Hausa br si i pọ ninu iṣẹ ṣọja, nnkan si tib yipada titi di bi a e wa loni-in yii.

Bawo ni wn waa e e e to ri bẹẹ? maa ka a l ls to n b

(349)

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.