Bẹẹ lawọn ọmọ Iya awusa ti wọn wa l’Ondo

Spread the love

Bo ti e ri fawn ara Ogun yii naa lo ri fawọn ara Ondo, nibi ti awn APC kan wa ti wn fẹẹ fyin Rotimi Akeredolu bal, ti wn fẹẹ fnu ja a niraw, wn ko si kohun yoowu to le da sil fgbẹ wn. Afi bii m awusa. ni ba ti ri awusa ri ninu ile r, yoo ri i pe bii ogun bii mẹẹẹdogun awusa le wa ninu ile kan, wn yoo j wa nib, ugbn wn yoo kyin sira wn debii pe kan ko ni i ri ekeji, bẹẹ ni ile kan ko ni i ja sile ekeji, ni to ba si gbe wọn dani yoo ro pe oun kan gbe paadi lasan dani ni, bẹẹ ni ọmọ awusa pọ ninu r, ugbọn awọn m awusa ti wọn wa ninu ile kan naa, ti wọn j mọọya kan naa yii ko m ara wn, wn o m oju ara wn, lati ibr aye wọn ni wn ti n kyin sira wọn. Bi ko ba waa j bẹẹ, kunrin kan ti yoo dupo gomina ni ipinl naa ldun to n b, Banji Ayiloge, ko rni ti yoo ba ja tabi ti yoo sr si ju gomina to wa nib l. O ni o n ba owo ninu j, o ni wn kowo j lasiko tir, ko si fi owo to n gba lAbuja e kinni kan. Bi kunrin naa ba m ni, yoo mọ pe ki ie Akeredolu loun n ba loju j, tabi ti oun n ba orukọ r j, gbẹ APC ni. Awọn araalu o m oun, wn ko si m orukọ r tabi ohun to fẹẹ e, Akeredolu ni wn m, orukọ APC ni wn yoo si maa darukọ pegbẹ ti ko dara ni, nitori awọn ti ba awngbẹ mi-in e tl, wọn e daadaa fawn. Bi Ayiloge yii ba m nipa oelu, gbogbo ariwo to ba fẹẹ pa, ati kampeeni to ba fẹẹ e, ki ie nita ni yoo tie e, inu ẹgbẹ APC ni yoo tie e, nitori awọn APC ni yoo fa a kal, bi APC ko ba fa a kal, ko le fi orukọ gbẹ wn dupo nibi kan. Nigba ta a ba n e oṣelu, ti a ba j wa ninu gbẹ kan naa, a ki i bu ara ni, afini to ba tietan ti yoo figbẹ naa sil lo ku, nitori oruk gbẹ ni ni to wa nijba naa fi n ejba r, bi o ba si jab, gbẹ APC lo jab yii. Eeyan ko tan ara r bii iya ibeji, bi Ayiloge ba ro pe oun yoo gba ipo lw Rotimi nipa bibu u pe ijba r ko dara, to si waa ro pe awn araalu yoo dibo fun APC bi wọn ba fa oun kal, ara r lo tan j. Bi Akeredolu ba ti jab, APC lo jab, bi iru Ayiloge ba si yju lati inu ẹgbẹ naa pe ki wn y oun wo, wn yoo ju u loko ni. Wahala to si wa niluu yii naa ni pe oṣelu jẹ-kinj la n e ni, ni ti ounj ko ba si ti yi kan, ibinu buruku ni. ugbọn keeyan o ma tori ipo ba agba j, nitori agba naa yoo kan oun naa bo dla.

(64)

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.