Awọn alakooso tuntun bẹrẹ iṣẹ lawọn kansu Ekiti

Spread the love

Lẹyin ti ile igbimọ aṣofin ipinlẹ Ekiti paṣẹ pe kawọn alaga kansu ijọba ibilẹ mẹrindinlogun to wa l’Ekiti lọọ sinmi nile, ki iwadii ijinlẹ le waye lori awọn ẹsun ti wọn fi kan wọn, awọn alakooso tuntun ti bẹrẹ iṣẹ.

Awọn mẹrindinlogun tijọba ni wọn yoo maa ṣagbatẹru gbogbo awọn eto ijọba ibilẹ lati mu iṣẹ tẹsiwaju ni wọn bẹrẹ iṣẹ lọsẹ to kọja.

Awọn alakooso ọhun ni:

 1. Ọgbẹni Andẹrọ S.O – Irẹpọdun/Ifelodun
 2. Ọgbẹni Akinwumi Foluṣọ – Ikẹrẹ
 3. Ọgbẹni Boriṣade Yinka – Guusu Iwọ-Oorun Ekiti
 4. Ọgbẹni Ṣẹsan Aina – Ado
 5. Ọgbẹni Ayọ Aluko – Ọyẹ
 6. Abilekọ Tọba Ojo – Mọba
 7. S Ọladunjoye – Isẹ-Ọrun
 8. Agbaje S. A – Ijero
 9. Ọgbẹni Arowolaju Tunde – Iwọ-Oorun Ekiti
 10. Ọgbẹni Adesọba F.O – Emure
 11. Ọgbẹni Ọwajọba J. O – Gbọnyin
 12. Ẹnjinia Akinọla Bayọ – Ido-Osi
 13. Ọgbẹni Fasanmi G.O –Ikọle
 14. Ọgbẹni Ogunṣakin L.R – Ẹfọn
 15. Ọgbẹni Williams Adeọla – Ilejemeje
 16. Alagba K.M Waleọla – Ila-Oorun Ekiti

 

 

 

(10)

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.