Agadagodo meji ti ki i finu han ara wọn

Spread the love

Agadagodo ni iya-kkr ti a fi n ti nnkan pa, bi eeyan ba si ri i ti wn ko meji agadagodo kal, ti wn e wn ni aw kan naa, ti wn ri bakan naa, oluwar yoo ro pe m-kkr kan naa ni yoo maa i gbogbo wn l ni. ugbọn ir ni, beeyan ba ti ki kkr b , yoo ri i pe m kkr kan ko ni i i agadagodo meji, inu ni agbara agadagodo wa, agadagodo meji ko si ni i fi inu han ara wn. Bi r awọn aṣaaju APC ipinlOgun ti ri nu-un. APC ni Ibikunle Amosun to e gomina tl, APC ni Dap Abidun to n e gomina lw, ugbọn ibi tir naa ti br to si pari si niyn, agadagodo ni wn, agadagodo meji kan ko si finu han ara wn. To ba j nibi ti nnkan ti daa ni, bi olori oril-ede yoo ba yan minisita sinu ijọba r, lati d gomina ni yoo ti mu ni ti yoo fie minisita yii, gomina gbọd fw si i ko too fi nikni e minisita tabi oludamran, nigba to j ipinlẹ r ni, oun  si ni alaṣẹ ipinlnaa, gbogboni yoowu ti yoo ba si ti ipinlẹ naa wa, ab r lo gbd ti jade, paapaa nigba to ba j gbẹ oṣelu kan naa ni wọn n ṣe. Ṣugbọnni ti Buhari mu to n e minisita, lati ipinl Ogun, thun ki i e aoju Abidun, aoju Amosun ni. Itum eyi ni pe ni yii ki ie aoju ipinl Ogun, aoju Amosun ni. Ko ni i lọọ jab fun gomina ipinlOgun, tabi ko lọọ fi r l , Amosun ni yoo maa fi r r l, bẹẹ ni ko si ni i e kinni kan fun wn ni ipinl Ogun, nitori ko ni i fẹ ti gomina, o m ohun ti oun n f, o kan wa nib bii aoju Amosun lasan ni. Amosun lo n lo agbara r yii, nitori r awn Buhari loun, o m awn iyawo r, o si m awọn m r, ati awn to sun m n, agbara ti oun n lo le gomina lori niyn. Ṣugbọn ko y ko ri bẹẹ. Wọn ki i e aye bẹẹ. Nigba ti Amosun n ejba r, ko sni to e bẹẹ fun un. Ati pe ohun to n e ko ni i tun ipinlẹ Ogun e, yoo ba ipinlẹ Ogun j ni. e Amosun fẹẹ ba ipinlOgun j nitori ni to fa kal ko wle ni! Abi iru agbara ilokulo, agbara ti ko wulo fnikan, to j ara r lo wulo fun wo leleyii! Ohun ti ni kan n e niyi naa ni yoo e t nij kan. Ki Amosun mura si i o, lj kan lawn eeyan ipinl Ogun yoo m pe aburu lo e fawn, afaim ki wn ma si l loko nigba tirnaa ba ye wn tan, Buhari ko si ni i si nitosi lati gba a sil, nigba ti awọn eeyan ba n ko aj to n da yii fun un.

(81)

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.