Ṣugbọn tawọn agbofinro yii lo buru ju, afi bii asasi

Spread the love

Am bi Lai ba duro to n s kantankantan, to n sr ti ko m itum r, to n pariwo nu nitori ko le maa e minista, ati ko le maa ri owo ilu na bo ṣe f, aweeyan yoo fori ji i toba ya, wn yoo mọ pe oloṣelu ni, ko si si ohun ti wn m oloelu Naijiria m ju ir ati tan lṢugbn eyi ti ko dara ni nigba ti awn agbofinro ba jade, paapaa awn ologun ni Naijiria, ti wn ba n sr lati ṣẹruba gbogbm Naijiria. Awọn ṣọja ti jade, awọntlmuy DSS, ti jade, awlpaa naa sr, wn ni awn kan fẹẹ fi tipatipa gbajbalw Buhari. Nie ni r naa n run leti, paapaa nigba ti eeyan ba n gb lati ibi to ti wa. rrirun gbaa, r ti ko gbe laakaye kankan lori ni. Ko yat si bii igba ti baba lanlọọdu kan ba gba sikiriti si ile r, ti sikiriti naa waa n s fun baba onile ati awm r pe oun ti mawn ti wn fẹẹ waa ko wn nile o, koda, oun ni ri lw pe wn ti de itosi ile wn. Ohun ti baba onile yoo s ni pe nigba to o m wn, to si m ibi ti wọn wa, ki lo n duro fun, ko jkawn tete lọọ mu wọn lojumm, ki il tou, ko too di pe we iṣẹ aburu wn. Biawọn eeyan yii e ri ree, nigba ti awṣọja ti ni ibn, ti wn ni agbara ijọba, ti wn nigbogbo ohun ti wn le fi mu onijangbọn abi adaluru, ba jade funra wn, ti wn ni awn ti m awn to fẹẹ dalu ru, awọn to fẹẹ fipa gbajba, ti wn ko si e kinni kan, ti wọn kmunikẹni, e wn n duro ki awọn eeyan naa fibn abi ipa gbajba looot ni. Ni gbogbo igba ti a ti wa ni Naijiria yii, ko sni to n gb iru ariwo bayii ld ijọba kan. Iru r ko waye ri. Biawn kan ba fẹẹ gbajba, awn ijọba yoo ti mu wn, igba ti wn ba mu wọn tan ni wọnyoo ṣẹṣẹ maa alayna ti wn fi fẹẹ gbajba naa faraalu, ti wn yoo si kọ ẹri kalugbọn nnkan lawṣọja ati awọn DSS aye Buhari yii o, awn tun yat si awnṣọja ti a ti n ri tl, apẹẹr pe ohun gbogbo si ti dorikodo ni Naijiria ni. Gbamigbami ko yagba, ranko n le mi in b wa ko y ọmọ dugbn ni ti awga ṣọja ti a ni ni Naijiria bayii, araalu nikan lawọn le hal m, wn ko le dewaju awBoko Haram, bẹẹ ni wn ko le sun mọ awọn Fulani apaayan, bi wn ba si ri maalu lasan, wn yoo h, nitori wn yoos pe ẹkun ogidan oloola iju lawn ri. Eyi ti a ko si yii, Ọlọrun nikan lo le gba wa.

(66)

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.