Ṣugbọn ta la ri ba wi, bi ko jẹ baba to fi ọmọ rẹ fọkọ loru

Spread the love

Baba kan wa nigba kan, o gba alejo kan sile r, lw al ni alejo naa de, bẹẹ lo ko plp ru ati iwfa dani. O ni oun n l si irin-ajo kan ni, ugbọn ilẹ ti u awọn sọna bayii, ki baale j ki awn sun mju. Inu baale dun, o ni oun gba alejo pataki, n lo ba br si i fi ile pnti lo n fi na roka, e o si ti ri i pe kunrin to de naa, apo nla nla bii marun-un ti wọn ko kal nib, owo lo kun inu r ff. Nibi ti wọn ti n alejo nikunrin lla naa ti taju kan-an to ri arwa m baba to gba wọn sile, n lo ba ni oun yoo f , bo ba e towo, oun yoo f , al jnaa loun yoo si f . Ninu apo owo meje o ko marun-un kal, loru ọjọ naa lo si fyawo r, n lo ba mu un l. Ae oko ole ni kunrin ti wn ro pe olowo ni yii ti n b, ni fẹẹr to si jana lati maa pada l plu awọn ero, pkin-rẹki loe plu awn d nla nla lati agbegbe ti wọn ti lọọ ja wn lole, ni wn ba fija pẹẹta. Nib ni wn pa kunrin igaara lọṣa naa si ati gbogbo awn to tle e. Itosi ilu ti wn ti kuro ni, ni gbogbo araadugbo ba jade, wn ba m baba to gba wọn lalejo, wn ti fibnakabula pa a. r naa ditan o dowe, wn ni ta la ri ba wi bi ko j ni to fm fk loru ti ko j kil o m. Bi South Afrika ba n hu iwa ibaj ti wn n hu yii, ta leeyan yoo ba wi bi ko j awn m Naijiria funra wn to j gbogbona pata ni wn n wa lati fi ilu yii sil, ti wn yoo fi ile wn silẹ, ti wn yoo si lọọ di ru nibomi-in, bo tilj awn ibi ti wn n l yii naa, aburu to maa n ba wn nigba mi-in a maa ju eyi ti wn le fnu alaye fni kankan l. Ati pe awn mi-in yoo tun de oril-ede mi-in yii, wn ko l sib lati huwa bii mluabi, iwa ole, idigunjale, jibiti-lilu, ka-fipa gbowo olowo, ka gbe oogun oloro, ati awọn iwa aburu mi-in ni wn yoo maa hu nib, ti awn onilu yoo si fi ri r s pe wn wa lati ba oril-ede awn j ni. Loni-in yii, ariwo ti awnm South Afrika n pa ni pe awn mNaijiria n gbe oogun oloro, wn n fipa gba awọn obinrin awn, wn n lu jibiti, wn n digunjale, wọn si ti fẹẹ ba oril-ede awọn j, wọn fẹẹ s awn da bi Naijiria ti da, nitori lawọne n ba wn ja, ti awn koe f wn m. Looot ki ie gbogbo m Naijiria lo n e bayii nib, ugbọn awọn ti wn j m buruku, ole ati igaara yii, awn m Ibo si ni o, awn ni wọn tub n ba nnkan j, awọn ni wn si fun awọn ọmọ South Afrika yii lr s. Looot ti awnm South Afrika yii wa lara wn, bi awọn ọmọ Naijiria ti wọn wa nib ko ba tepele m iwa ibaj, r naa iba dun lati s. j ka kil fun awọn ọmọ tiwa naa, ki wn ma huwa ti yoo ba oril-ede awn to gba wn lalejo j, nitori bi wọn ba ne bẹẹ, bi yoo ti maa ṣẹl si wn naa ree, gbogbo ohun ti wn ba ko j, lj kan lawn yn yoo ba a j m wn lw, iyn ti wn ko ba til gba mi wn. m onile aa t jẹẹj, ajoji ni i t girigiri, kawọn m Naijiria ṣọra wn lyin odi.

(26)

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.