Ṣebi ẹyin naa gbọ ti Dino Melaye ni Kogi

Spread the love

O fr j pe ko si kinni kan ti awn oloelu Naijiria ko ni i fi ọw ibaj kan. Eyi to si buru to j yoo pada waa kan gbogbo eeyan il yii naa ni ti etoidaj. Wn ti s awn adaj wa di nnkan mi-in, iba di, iyẹn to ba tilwa rara, lo ku tn daj ododo. Bẹẹ ni oril-ede ti ko ba ti si idaj ododo, ib yoo egbe, ki Ọlrun ma j ki Naijiria ṣegbe ni. Ohuto ba foju han, ti gbogbaye ri, ti wn si m pe eleyii ni ododo, awọn adaj wa yoo jokoo, lyin tiwn ba ti gbowo lw awọn oloṣelu tan, tabi ti awn ti wn n ejba ba ti hal m wn, wn yoo ni kinni naa ki i ṣe ododo, nitori lasiko to ṣẹllrii to sr yn ko ltọọ lati srKi i ṣe pe wnlrii yn ko s ododo o,ugbọn pe ko ltọọ lati sr ni. Iyni wn yoe pal ododo m, ti wn yoo si fi ir rpo r. Ibo ti gbogbo awọn ara Kogi ri, ti wn si fi tkan-tara wn dibo fun Dino Melaye, awn igbim ti wn gbe dide nibẹ latedaj ni ibo nani ko daa, Dino kọ lo wle nib. Gbogbo aye mgbọn wn, na lati di Dino Melaye lw ko ma le dupo gomina tofẹẹ du ni, ati ọna lati ja a kul pata ko ma j nnkan kan m. O ee e kiDino Melaye ma daa, ko j alariwo ati alafyy kan ti ko til y ko sunm ile ijba. ugbọn lnu-rirun lo ni amu iya r, bi awọn araalu r atiagbegbe r ba s pni ti awn n f ko waa lọọ e oju awnibikibi ree, gẹgẹ bii eto ijba dmokiresi ti a n e yii, ko snikan to ltọọ labofin lati di i lw, nitorki i e awn ni wn yan an, awọn araalu r ni.ugbọn igba tawọn adaj ba ti j ijkuj, iskus lo ku ti wn yomaas, idaj ododo yoo si snu m wn lagbari, ir ni yoo ku nib, wnyoo si maa i gbogbo wa lna kaakiri. O digba ti awn adaj wa ba laya lati e idaj ododo, ti wn ko si gbowo ẹyin, ti wn n daj are fun olododo, ti wn si n da bi fun alaiododo, nigba naa ni oril-ede yii yoo dara gan-an. Bi Naijiria ba dara, awadaj yii ni ki ẹ ki, bi Naijiriaba si bajẹ, awn adaj yii naa ni ki  mu o.

(17)

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.