Ṣe oye idile ni, abi ewo ni Shittu n wi yii o

Spread the love

Minisita tl, Adebay Shittu, ni nie laya oun lu kii nigba ti ko si orukoun ninu awn minisita tuntun ti wn ṣẹṣẹ yan, o ni oun ti ro pe AarBuhari yoo tun oun yan lẹẹkeji ni. Lara awọn ti wn m ofin, ti wn n ru ofin ti a n wi ree o. Abi bawo ni Shittu yoo e ro pe ki wn tun yan oun lẹẹkeji. Akk ti wn yan an, ariwo lo mu wa, to ba si j ibi ti ijba ilẹ yiiti daa ni, gbogbo owoou to gba, ati awn ajmnu oriṣiiriṣii to ko sapo nigba to fi n e minisita akk yii, gbogbo ẹ lo y kwn gba pada lw r. Asiko to e minisita ni wn fi sun kan an pe ko ṣe iṣẹagunbanir to yẹ ko ṣe ko too br si i fi sabukeeti r iṣẹ. kunrin yii ko ri esi kankan mu sil ju pe nigba ti oun jade, iṣẹ ijọba loun ri, oun si ti ro pe gbogbo ẹni to ba n iṣẹ ijba n iṣẹ sin ilẹ baba r ni. Lọọya ni o, o si m pe ir loun n pa. O m lkan ara r pe r naa ki i e bẹẹ,nikni to ba e agunbanir ki i gba owoou, bẹẹ ni iṣẹ ijba yat si iṣẹ awn to n sin il baba wn. Nigba ti Buhari ko si mu un yii, to lọọ y lnu, o jọ pe kinni naa ti di oye idile niyn o.  ri awn oloṣelu yii, nnkan wa lara wọn ni o!

(8)

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.